Wale Ojo
Wale Ojo jẹ́ òṣèré orílẹ̀-èdè Nàìjíríà àti Britain. Ó bẹ̀rẹ̀ eré ṣíṣẹ láti ìgbà tó wà lọ́mọdé lórí ẹ̀rọ amóhùnmáwòrán. Ó tẹ̀síwájú láti máa ṣe eré ní UK àti Nàìjíríà.[1][2] Ó bọ́ sí gbàgede ní ọdún 1995 fún kíkópa tí ó kópa nínú fíìmù The Hard Case. Ó gba àmì ẹ̀yẹ fún òṣèrékùnrin tó dára jù lọ ní ọdún 2012 ní 2012 Nigeria Entertainment Awards.[3][4]
Wale Ojo | |
---|---|
Wale Ojo | |
Orílẹ̀-èdè | British-Nigerian |
Ọmọ orílẹ̀-èdè | United Kingdom, Nigeria |
Iléẹ̀kọ́ gíga | University of Hull, (Drama, 1986) |
Iṣẹ́ |
|
Ìgbà iṣẹ́ | 1976 to present |
Gbajúmọ̀ fún | Phone Swap (film) |
Ìbẹ̀rẹ̀pẹ̀pẹ̀ àti ètò-ẹ̀kọ́ rẹ̀
àtúnṣeỌjọ́ bẹ̀rẹ̀ sí ní ṣe eré láti ọmọdé. Nígbà tí ó wà ní ọmọ ọdún mẹ́jọ, ó bá Akin Lewis ṣiṣẹ́ tí ó ṣe agẹrun nínú eré why worry lórí NTA Ibadan ní ọdún 1980. Nígbà tí ó pé ọmọdún méjìlá, ó kó lọ sí England pẹ̀lú àwọn mọ̀lẹ́bí rẹ̀ níbi tí ó ti lọ ilé-ìwé gíga.[5]
Ojo gbóríyìn fún ìyá rẹ̀ tó jẹ́ òṣèré tí ó sì ṣe àtìlẹ́yìn fún nínú iṣẹ́ òṣèré rẹ̀,[6] ó sì tún mẹ́nuba àwọn èèyàn bíi Chief Wale Ogunyemi, Tunji Oyelana, akọ̀wé ìtàn Wole Soyinka, àti Zulu Sofola gẹ́gẹ́ bí àwọn ẹni tí ó ràn án lọ́wọ́.[5]
New Nigeria Cinema
àtúnṣeỌjọ́ dá New Nigeria Cinema ṣílẹ̀, èròǹgbà rẹ̀ sì ni láti mú kí àwọn fíìmù orílẹ̀-èdè Nàìjíríà dára si. New Nigeria Cinema ti ṣe ìgbàlejò ìwo fíìmù àti ìdánilẹ́kọ̀ọ́ ní British Film Institute ní London ní ọdún 2010.[7][8]
Àwọn iṣẹ́ rẹ́
àtúnṣeTV programs
àtúnṣeYear | TV Program | Role | Notes |
---|---|---|---|
1989 | Behaving Badly | Jim | Television mini-serial |
1998 – 2000 | Heartburn Hotel | Chidi Ekechi | Television serial |
2009 | The No. 1 Ladies' Detective Agency (TV_series) | Kebone Legodimo[9] | |
2012 - 2016 | Meet the Adebanjos | Mr. Bayo Adebanjo | British-Nigerian sitcom from 2012-2016.[10] |
2014 | Tinsel (TV series) | Nosa[11] | Long-running Nigerian soap opera |
2018 | Black Earth Rising | Dr. Emmanuel Musoni[12] | BBC Two production |
Films
àtúnṣeYear | Film | Role | Notes |
---|---|---|---|
1995 | The Hard Case | The gambler | Short film |
1999 | Rage (1999 film) | Pin | Ojo's first feature film debut. He plays a schizophrenic gangster.[13] |
2011 | "Johnny English Reborn" | President Chambal | |
2011 | The Guard | Doctor Oleyuwo[14] | Irish buddy film starring Brendan Gleeson, Don Cheadle. |
2012 | Phone Swap | Akin | Also featured Nse Ikpe Etim, Joke Silva, Chika Okpala, Lydia Forson and Hafeez Oyetoro. This was Ojo's first feature film in Nigeria.[15] |
2012 | Big Man | ||
2013 | Half of a Yellow Sun (film) | Chief Okonji | Historical film featuring Chiwetel Ejiofor, Thandie Newton, Onyeka Onwenu, Anika Noni Rose, Joseph Mawle, Genevieve Nnaji, OC Ukeje and John Boyega.[16] |
2014 | A Letter from Adam | Adam | Romance staring Lydia Forson (who also wrote the screenplay),Naa Ashokor Mensah Doku, Akorfa Edjeani, Albert Jackson, Fred Kanebi, Jeff Kumordzie and Louie Lartey. |
2014 | Render to Caesar | Pade | Crime thriller also featuring Gbenga Akinnagbe, Omoni Oboli and Bimbo Manuel |
2014 | When Love Happens | Oladele Laguda | Romantic comedy featuring Weruche Opia as Moduroti (Mo) Bankole-Smith |
2015 | 8 Bars and a Clef | Felix Mensah | Film about a musically gifted recording artist dealing with dyslexia.[17] |
2015 | Fifty (film) | Kunle | Stars Iretiola Doyle, Nse Ikpe-Etim, Dakore Egbuson |
2016 | Ayamma: Music in the Forest | Prince Daraima | |
2016 | Ojukokoro | Mad Dog Max | This crime film is also known as Ojukokoro: Greed and includes an ensemble cast. |
2016 | The CEO | Kola Alabi | |
2016 | White Colour Black | Monsiour Dabo | Also starring Dudley O’Shaughnessy as the main character.[18] |
2017 | Alter Ego (2017 film) | Timothy | |
2017 | Sand Castle | Ayade | Also starring Mary Uranta and Sylvia Edem. |
2017 | Ghost of Tarkwa Bay | Nigeria’s first movie about the art of surfing. Also features Ibrahim Odrago, May Owen, Armando Abraham, and Godspower. This short film marks Wale Ojo's directorial debut.[19][20] | |
2018 | New Money (2018 film) | Chuka | Also stars stars Jemima Osunde, Kate Henshaw, Blossom Chukwujekwu, Dakore Akande, Osas Ighodaro and Falz d Bahd Guy.[21] |
2018 | Lara and the Beat | Uncle Tunde | |
2018 | Disguise | Theophilus Vaughn | |
2019 | Another Father's Day | Femi Daniel | Sequel to Happy Father's Day film. Directed by Bukola Ogunsola. Also stars Mercy Aigbe.[22] |
2019 | Don't Get Made Get Even | Dr. Badejo[23] | Ojo's feature film directorial debut. Features Toyin Abraham, Saheed Balogun and Nancy Isime. |
2019 | Jumbled | ||
2019 | Kasanova | Femi[24] | Also starring Iretiola Doyle, Toyin Abraham, Ruby Akubueze and Yomi Alvin. |
2019 | Ordinary Fellows | Professor Jega | A film by Lorenzo Menakaya |
2020 | This Lady Called Life | Daddy[25] | Stars Bisola Aiyeola, Samuel Asa'ah, and Lota Chukwu. |
Theatre
àtúnṣeYear | Play | Theatre | Role | Notes |
---|---|---|---|---|
2009 | The Sunset Limited[26] | Capital Centre, Warwickshire, England | Black | Michael Gould performed as White |
Àwọn àmì-ẹyẹ rẹ̀
àtúnṣeYear | Event | Prize | Work | Result |
---|---|---|---|---|
2012 | Nigeria Entertainment Awards | Best Actor in a Film | Phone Swap | Gbàá[27] |
Àwọn Ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ Laju Ayenreka (December 21, 2012). "A wife for Wale Ojo". The Vanguard.
- ↑ "I started acting 40 years ago with NTA Ibadan wale ojo". Nigeria Entertainment Today. Retrieved 13 May 2017.
- ↑ "Photos + Full List Of Winners At The NEA". 2012.
- ↑ Shaibu Husseini (July 16, 2016). "Wale Ojo: ‘The CEO’ and Nollywood’s new leading man". The Guardian.
- ↑ 5.0 5.1 "Wale Ojo: ‘The CEO’ and Nollywood’s new leading man". The Guardian Nigeria News - Nigeria and World News. 16 July 2016. Archived from the original on 24 October 2020. Retrieved 22 March 2021.
- ↑ "Wale Ojo". Africa Interviews. Retrieved 22 March 2021.
- ↑ Krings, Matthias; Okome, Onookome (in en). Global Nollywood: The Transnational Dimensions of an African Video Film Industry. Indiana University Press. p. 43. ISBN 978-0-253-00942-5. https://books.google.com/books?id=uTVlKirJmGgC&pg=PA43. Retrieved 22 March 2021.
- ↑ Curry, Neil (19 Nov 2010). "'New Nigeria Cinema' sparks Nollywood renaissance" (in en). www.cnn.com. http://www.cnn.com/2010/SHOWBIZ/Movies/11/19/nigeria.nollywood.film/index.html.
- ↑ "The No. 1 Ladies' Detective Agency". TVGuide.com (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 21 March 2021.
- ↑ Guide, British Comedy. "Meet The Adebanjos - Netflix Sitcom". British Comedy Guide. Retrieved 21 March 2021.
- ↑ "Wale Ojo sails with Tinsel". Businessday NG. 6 July 2014. Retrieved 22 March 2021.
- ↑ "Black Earth Rising (TV Series 2018) - IMDb". imdb.com. Retrieved 21 March 2021.
- ↑ "Wale Ojo". IMDb. Retrieved 21 March 2021.
- ↑ "The Guard (2011) - IMDb". Retrieved 22 March 2021.
- ↑ "Wale Ojo". IMDb. Retrieved 21 March 2021.
- ↑ "Half of a Yellow Sun: London Review". The Hollywood Reporter. 11 October 2013. Retrieved 28 March 2014.
- ↑ "8 Bars & A Clef (2015) - IMDb". imdb.com. Retrieved 21 March 2021.
- ↑ Contributor, Guest. "Joseph A. Adesunloye’s Feature, White colour Black, Gets UK Premiere at #LFF2016. | The British Blacklist". thebritishblacklist.co.uk. Retrieved 21 March 2021.
- ↑ "New Nigeria Cinema hits National Film Theatre Southbank". African Voice Newspaper. 22 November 2017. Retrieved 22 March 2021.
- ↑ "EXCLUSIVE INTERVIEW WITH WALE OJO". Bespoke Event Guide. 7 November 2017. Retrieved 22 March 2021.
- ↑ Daniel, Eniola (21 March 2018). "Veterans, newbies clash in New Money". Guardian. https://m.guardian.ng/art/veterans-newbies-clash-in-new-money/.
- ↑ "Watch Official Trailer for “Another Father’s Day” starring Wale Ojo, Cee-C, Mercy Aigbe". BellaNaija. 17 April 2019. Retrieved 22 March 2021.
- ↑ Ojo, Wale (3 October 2019). "Don't Get Mad Get Even". RGD Media Productions. Retrieved 22 March 2021.
- ↑ Asurf, Oluseyi (13 September 2019). "Kasanova". Asurf Films. Retrieved 22 March 2021.
- ↑ Kasum, Kayode (15 May 2020). "This Lady Called Life". AzureNoir&Co, Film Trybe. Retrieved 22 March 2021.
- ↑ Josyph, Peter (2011). "Now Let's Talk about "The Sunset Limited": An Exchange With Marty Priola". The Cormac McCarthy Journal 9 (1): 66–86. ISSN 2333-3073. https://www.jstor.org/stable/42909426. Retrieved 21 March 2021.
- ↑ "Photos + Full List Of Winners At The NEA". Information Nigeria. 4 September 2012. Retrieved 21 March 2021.