The Joneses jẹ fiimu ere-awada 2009 ti Amẹrika ti Derrick Borte kọ ti otun si daari, ninu ise oludaari akoko rẹ. Awon oshere bi Demi Moore, David Duchovny, Amber Heard ati Ben Hollingsworth.[1] O ṣe afihan ni ayeye Toronto International Film ni Oṣu Kẹsan ọjọ ketala, Ọdun 2009.[2]Awon Roadside Attractions ra ẹtọ pinpin fiimu na ni itage ti ile Amẹrika.[3] O afiihan oni suuwan ni Oṣu Kẹrin Ọjọ kerindinlogun, Ọdun 2010[4]won si se afiihan re ni siinu DVD ati Blu-ray Ni Oṣu Kẹjọ Ọjọ keewa, Ọdun 2010.[5]O gba affihan ori itage ni Ilu Meksiko ni Oṣu Kẹjọ Ọjọ ogun, Ọdun 2010.

Ahunpo Itan

àtúnṣe

Kate, Steve, Mick, ati Jenn Jones kolo si igberiko labẹ etan pe won je idile to kowa tori iyinpada iru ise ti Kate ati Steve nse. Ni otitọ, Kate jẹ oludari ẹgbẹ kan ti won je ataja lori etan, awọn onimo oniṣowo ti o paarọ taaja bi ise ojoojumọ won. Aṣọ wọn, awọn ẹya ẹrọ, aga, ati paapaa ounjẹ ni a ti gbero ni pẹkipẹki ati ti won gba lowo ile-iṣẹ orisirisi lati ṣẹda affihan ti awon ara oja maa feeran. Lakoko ti ẹgbẹ Kate jẹ doko gidi, Steve sese dara po mon ẹgbẹ naa.

Awọn egbe ni kiakia fowo wewo peelu awujo titun yii, deebi pe, awon olutaja agbegbe na hun ra nkan ti won ba ti ri lara egbe yii sinu soobu won. Sibẹsibẹ, ni ipari atunyẹwo ojo ogbon, Steve ṣe iwari pe oun lota oja ti okere ju ninu ẹgbẹ naa, ati pe iṣẹ Kate wa ninu ewu ayafi ti o ba le taa daadaa ju bayii lo ṣaaju atunyẹwo ojo ogota to un bo. Nikẹhin, Steve bẹrẹ lati wa ilana tita kan ti o ṣiṣẹ nipa ṣiṣere lori awọn ibẹru ti awọn aradugbo rẹ ati ibakẹdun pẹlu ṣigọgọ wọn. Gẹgẹbi ẹnikan ti o ni ibanujẹ pẹlu iṣẹ rẹ, Steve yipada si awọn ọja wọn lati jẹ ki inu re dun. Nigbati o ri ilana kanna ni awọn aladugbo rẹ, oja tita rẹ bẹrẹ lati pọ si nitori o polowo awọn ọja re fun ojutu ai nidunu won ni igberiko na.

Awon Osere

àtúnṣe

Ṣiṣejade

àtúnṣe

Ṣiṣejade bẹrẹ ni Oṣu Kẹwa 2008, ni Alpharetta, Georgia.[6]

Duchovny sọ pe oun ati Moore kọọkan ni ile nla fun ara wọn lakoko ti o nya aworan. "O jẹ agbegbe ti a gbero ti McMansions, ti a ko ni akoko opo owo ati ni ode oni o ko si ero pupo nibe. Nitorina a kan gbe sinu diẹ ninu awọn ile nla nla wọnyi, ”Duchovny lo so be.[7]

Awọn itọkasi

àtúnṣe
  1. Borys, Kit (September 19, 2008). "Trio joins 'Joneses'; David Duchovny, Demi Moore, Amber Heard in cast". The Hollywood Reporter. Nielsen Business Media. Archived from the original on February 13, 2010. Retrieved February 26, 2010.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  2. "TIFF - Toronto Internationals Film Festival - Joneses". 2009 TIFF. September 13, 2009. Archived from the original on February 25, 2010. Retrieved February 26, 2010.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  3. Swart, Sharon (November 4, 2009). "Roadside Attractions acquires 'Joneses'". Variety (Reed Business Information). https://www.variety.com/article/VR1118010858.html?categoryid=13&cs=1. Retrieved February 26, 2010. 
  4. "The Joneses - Release Date". ComingSoon.net. CraveOnline. Archived from the original on January 22, 2010. Retrieved February 26, 2010. 
  5. "The Joneses (2009)". 
  6. Richard L. Eldredge (April 15, 2010). "Shot-in-Alpharetta comedy ‘The Joneses’ shops for an audience". Atlanta Magazine. 

  7. Aaron Broverman (April 16, 2010). "Duchovny, Moore had mansions for 'Joneses'". Digital Spy.