New Telegraph

(Àtúnjúwe láti The New Telegraph)

The New Telegraph jẹ́ ìwé ìròyìn ti gbogbo orílẹ̀-èdè ní Nàìjíríà, pẹ̀lú ìtajà àtẹ̀jáde tó tó ọgọ̀rún-ẹgbẹ̀rún ní ọjọ́ kan.

New Telegraph
TypeDaily newspaper
FormatBroadsheet
PublisherDr. Uzor Kalu
EditorJuliet Bumah
Editor-in-chiefMr. Ayodele Aminu
FoundedOctober 2013
LanguageEnglish
HeadquartersLagos, Nigeria
Official websitehttp://newtelegraphng.com

The New Telegraph fojú sí àwọn òǹkàwé Nàìjíríà àti àwọn òǹkàwé àjèjì nínú àti láàárín àyíká àwọn ilé-iṣẹ́ ìlú ti orílẹ̀-èdè, àti ní káríayé, àti pé ó ní èrò láti pèsè ibi-afẹ́dé àti ìdáwọlé ti títẹ̀ àwọn ọ̀rọ̀ ìṣèlú àti àṣà àwùjọ tó ṣe kókó.[1]

Dr Orji Uzor Kalu ni alága The New Telegraph àti pé ó ṣe ẹ̀yà olókìkí àwọn èèyàn pàtàkì inú orílẹ̀-èdè àti ní àjèjì, pẹ̀lú Àgbẹjọ́rò ẹ̀tọ́ ènìyàn, Emmanuel Onwe. .[2]

Ìjàpọ̀ Mìíràn

àtúnṣe

Ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. "New Telegraph, Nigeria's First Independent Political Broadsheet Out Today". African Herald Express. 2014-02-03. Archived from the original on 2014-04-27. https://web.archive.org/web/20140427010719/http://africanheraldexpress.com/blog8/2014/02/03/new-telegraph-nigerias-first-independent-broadsheet-out-today/. Retrieved 2014-04-25. 
  2. "Boko Haram: The commander-in-chief in the shadow of war crimes". New Telegraph. 2014-03-22. Archived from the original on 2014-04-26. https://web.archive.org/web/20140426214956/http://newtelegraphonline.com/boko-haram-the-commander-in-chief-in-the-shadow-of-war-crimes/. Retrieved 2014-04-25.