Orji Uzor Kalu
Olóṣèlú Nàìjíríà
Orji Uzor Kalu (tí wọ́n bí ní Ọjọ́ kọkànlélógún oṣù kẹrin ọdún 1960) jẹ́ olóṣèlú ọmọ bíbí ìpínlẹ̀ Abia lórílẹ̀ èdè Nàìjíríà. Ṣáà méjì ọ̀tọ̀ọ̀tọ̀ ló lò gẹ́gẹ́ bí Gómìnà ìpínlẹ̀ Abia. Lọ́dún 2019, ó díje dùpò Sínétọ̀ lábẹ́ ẹgbẹ́ òṣèlú All Progressives Congress, ó sìn wọlé. Lọ́jọ́ karùn-ún oṣù Kejìlá ọdún 2019, ilé ẹjọ́ dá a lẹ́bi ẹsùn jìbìtì owó tí ìjọba àpapọ̀ fi kàn án, wọ́n sì fi i sẹ́wọ̀n ọdún méjìlá gbáko. [1]
Orji Uzor Kalu | |
---|---|
7th Gómìnà ìpínlẹ̀ Abia | |
In office May 29, 1999 – May 29, 2007 | |
Asíwájú | Anthony Obi |
Arọ́pò | Theodore Orji |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọjọ́ìbí | 21 Oṣù Kẹrin 1960 Abia State, Nigeria |
Ẹgbẹ́ olóṣèlú | People's Democratic Party (1st and 2nd terms). Formed Progressive Peoples Alliance(PPA) as a political party in July 2006 and contested as the party's presidential candidate in 2007. |
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
Àwọn Ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ "Orji Uzor Kalu gets 12 years imprisonment - Nigeria and World News". The Guardian Nigeria News - Nigeria and World News. 2019-12-05. Retrieved 2019-12-05.