Theodoros Pangalos (ọ̀gágun)

(Àtúnjúwe láti Theodoros Pangalos (general))

Theodoros Pangalos (Gíríkì: Θεόδωρος Πάγκαλος) (11 January 1878 – 26 February 1952) jẹ́ Alákóso Àgbà ati Aare orílẹ̀-èdè Gríìsì tẹ́lẹ̀.

Theodoros Pangalos.