Tigran Sargsyan (Arméníà: Տիգրան Սարգսյան, ojoibi January 29, 1960) ni Alakoso Agba ile Armenia lati 9 Osu Kerin 2008. Ko ni ibatan mo Aare ile Armenia Serzh Sargsyan.

Tigran Sargsyan
Տիգրան Սարգսյան
Alakoso Agba ile Armenia
Lọ́wọ́lọ́wọ́
Ó gun orí àga
9 April 2008
ÀàrẹSerzh Sargsyan
AsíwájúSerzh Sargsyan
Àwọn àlàyé onítòhún
Ọjọ́ìbí29 Oṣù Kínní 1960 (1960-01-29) (ọmọ ọdún 64)
Kirovakan, Soviet Union (now Vanadzor, Armenia)
Ẹgbẹ́ olóṣèlúRepublican Party of Armenia
Alma materVoznesenski Leningrad Institute of Economics and Finance


Itokasi àtúnṣe