Timini Egbuson Tí wọ́n bí ní ọjọ́ Kẹwàá oṣù Kẹfà ọdún 1987, jẹ́ òṣèré orí-ìtàgé, olùgbéré-jáde àti olùàiṣẹ́ lórí ẹ̀rọ ayélujára. [1]

Timini Egbuson
Ọjọ́ìbíJames Timini Egbuson
June 10, 1987 (1987-06-10) (ọmọ ọdún 37)
Bayelsa State, Nàìjíríà
Iléẹ̀kọ́ gígaUniversity of Lagos
Iṣẹ́
  • Actor
  • Producer
  • Digital Creator
Ìgbà iṣẹ́2009-present
Gbajúmọ̀ fúnElevator Baby, Shuga, Fifty, Skinny Girl in Transit, Manhunting with Mum, Tinsel ,Sophia
Àwọn olùbátanDakore Àkàndé (sister)
Websitetiminiegbuson.com

Ìbẹ̀rẹ̀ ayé rẹ̀

àtúnṣe

Wọ́n bí Timini ní Ìpínlẹ̀ Bayelsa, ó jẹ́ àbúrò fún gbajú-gbajà òṣèré Dakore Egbuson Àkàndé.[2] Ó lọ sí ilé-ẹ̀kọ́ alákọ̀ọ́bẹ̀rẹ̀ ti Greenspring Montessori, The Afro School and St Catherine's. Ó tún l9 sí ilé-ẹ̀kọ́ girama ti Adebayo Mokuolu CollegeÌpínlẹ̀ Èkó. Ó kàwé gboyè àkọ́kọ́ nínú ìmọ̀ Psychology ní ilé-ẹ̀kọ́ Fásitì ti Ìpínlẹ̀ Èkó.[3] Ó sì jáde ní ọdún 2011. Ó bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ eré ìtàgé ṣíṣe ní ọdún 2010 nígbà rtí ó kópa nínú eré onípele àtìgbà-dégbà ti Tinsel. Timini gba amì-ẹ̀yẹ ti AMVCA awards fún Òṣèrékúnrin tí ó peregedé jùlọ 0àá pàá jùlọ fún ipa tí ó kó nínú eré Elevator baby.[4]

Àwọn àṣàyàn eré rẹ̀

àtúnṣe

Timini ti kópa nínú àwọn eré tí ó ti pọ̀ [5]

  • "MTv Shuga"
  • "Fifty"
  • "Skinny Girl in Transit"
  • "Manhunting with Mum"
  • "Tinsel"
  • "Fifty the series"
  • "Isoken"
  • "Something Wicked"
  • "Another Time"
  • "Room 420"
  • "Ajuwaya"
  • "the missing piece"
  • "the intern"
  • "Elevator Baby"
  • "The girl code"

Awards and Nominations

àtúnṣe
Year Event Prize Result
2017 City People Award[6] Best New Actor of the year Nominated
2019 The Future Awards Africa Prize for Acting Won
2020 AMVCA awards[4] Best Actor in a Drama(Movie/TV series) Won

Àwọn Ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. "Timini Egbuson: Biography And Success Journey Of Nollywood's Finest". Entrepreneurs. 2019-10-20. Retrieved 2020-11-03. 
  2. "Timini Egbuson Biography and Profile - Nairagent.com". Naira Gent. 2019-09-22. Archived from the original on 2020-06-09. Retrieved 2020-11-03. 
  3. "WHO IS TIMINI EGBUSON? BIOGRAPHY/PROFILE/HISTORY OF NOLLYWOOD ACTOR TIMINI EGBUSON". dailymedia.com. Daily Media. Archived from the original on 2017-12-19. Retrieved 2020-11-03. 
  4. 4.0 4.1 "Africa! Here Are Your Winners at the 7th AMVCAs". Africa Magic - Africa! Here Are Your Winners at the 7th AMVCAs (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2020-03-23. 
  5. "Timini Egbuson on IMBd". 
  6. "City People Releases Nomination List For 2017 Movie Awards - City People Magazine". citypeopleonline.com. 8 September 2017. 

Àdàkọ:Authority control


Àdàkọ:Nigeria-actor-stub