Dakore Egbuson-Akande

Òṣéré orí ìtàgé
(Àtúnjúwe láti Dakore Egbuson Àkàndé)

Dakore Egbuson-Akande (tí orúkọ rẹ̀ tẹ́lẹ̀ ń jẹ́ Dakore Omobola Egbuson) jẹ́ Òṣèré Nigeria.[1][2] Ó jẹ́ aṣojú fún Amnesty Internation, Amstel Malta àti Oxfam ní America.[3]

Dakore Egbuson-Akande
Egbuson-Akande ni AMVCA odun 2020
Ọjọ́ìbíOctober 14, 1978 (1978-10-14) (ọmọ ọdún 46)
Bayelsa State
Ọmọ orílẹ̀-èdèNigeria
Iṣẹ́Osere
Ìgbà iṣẹ́1999 titi di bayi
Notable workMen do Cry
Olólùfẹ́Olumide Akande 2011 titi di bayi
Àwọn olùbátanTimini Egbuson (omo iya)

Igbesiaye

àtúnṣe

Ìpínlẹ̀ Bàyélsà ni wọ́n bí Dakore si, gẹ́gẹ́ bíi àkọ́bí àwọn òbí rẹ̀. Ó lọ sí ilé-ìwé Corona àti ilé-ìwé ìjọba Àpapọ̀ fún àwọn ọmọ obìnrin ní Ìpínlẹ̀ Èkó ati Ìpínlẹ̀ Bauchi[4] Ní ilé-ẹ̀kọ́ gíga, ó kọ́ ìmọ̀ ìbanisọ̀rọ̀ ní Fáṣítì Èkó ṣùgbọ́n kò parí ẹ̀kọ́ rẹ̀ nitorí igbélé gbogbo ìgbà [5] Ó ti ṣe ìgbéyàwó báyìí, Ó sì ti bí ọmọ méjì[6][7]

Ní oṣù kẹsàn-án ọdún 2019, wọ́n ṣe àfihàn Dakorae nínu ìwé àwòrán ti Visual Collaborative, nínu ìpele tí wọ́n pè ní Vivencias tí ó "Ìrírí" ni Èdè Spéìn. Nínu ìfọ̀rọ̀wánilẹ́nuwọ̀ pẹ̀lú àwọn ọgbọ́n ènìyàn láti oríṣiríṣi ìlú gẹ́gẹ́ bíi Kelli Ali, Adelaide Damoah àti Desdamona[8] Ní oṣù karùn-ún ọdún 2020 wọ́n tún ìfọ̀rọ̀wánilẹ́nuwọ̀ náà gbé jáde lórí Visual Collaborative, tí wọ́n pè ní TwentyEightyFour, tí wọ́n ṣe àgbẹ́jáde rẹ̀ nígbà Àrún èrànkòrónà ọdún 2019, olórin èdè faranse Les Nubians, akọrin ti Japan Rika Muranaka àti aláwàdà ilẹ̀ Nàìjíríà Chigul jáde nínu ìpele kan náà.[9]

Asayan Ere

àtúnṣe

Dakore ti ko ipa ninu fiimu ti o ju aadota lọ, diẹ ninu eyiti o pẹlu: [10]

  • Peace of Flesh
  • Men do Cry
  • Emotional Crack
  • Shattered Illusion
  • When the Going gets Tough
  • Playboy
  • Oracle
  • Hole in the Heart
  • Silent Tears
  • 11 days & 11 Nights
  • Operation KTP
  • Playboy
  • Silent Tears
  • Emotional Cry
  • Caught in the Middle (2007)
  • Journey to Self (2013)
  • Lunch Time Heroes (2015)
  • Fifty (2015)
  • Isoken (2017)
  • Chief Daddy (2018)
  • New Money (2018)
  • The Set Up (2019)
  • Coming From Insanity

Àwọn amì-ẹ̀yẹ àti ìfisọrí rẹ̀

àtúnṣe
Ọdún Ayẹyẹ Amì-ẹ̀yẹ Ẹni tí ó gbàá Èsì
2014 ELOY Awards[11] Brand Ambassador of the Year (Pampers) N/A Wọ́n pèé

Awọn itọkasi

àtúnṣe
  1. "I Missed acting - Dakore". informationng.com. Retrieved 19 May 2014. 
  2. "Dakore Egbuson is Back". punchng.com. Archived from the original on 19 May 2014. Retrieved 19 May 2014.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  3. "Dakore reappears in Journey to Self". vanguardngr.com. Retrieved 19 May 2014. 
  4. "Dakore Akande rocks Baby bump". thenationonlineng.net. Retrieved 19 May 2014. 
  5. "I never prepared to be famous - Dakore Akande". modernghana.com. Retrieved 19 May 2014. 
  6. "Becoming Mrs Akande, Dakore opens up with Life, career & motherhood". bellanaija.com. Retrieved 19 May 2014. 
  7. "I won't romance & kiss anymore in films - Dakore". dailystar.com.ng. Archived from the original on 19 May 2014. Retrieved 19 May 2014. 
  8. "Dakore Egbuson-Akande, Swaady Martin, others catalogued in Vicencias". June 19, 2019. Archived from the original on 2019-11-14. Retrieved September 7, 2019.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  9. Onyekwelu, Stephen (6 May 2020). "Les Nubians, Rika, Chigul, Dakore feature in TwentyEightyFour". Business Day (Nigeria). https://businessday.ng/life-arts/article/les-nubians-rika-chigul-dakore-feature-in-twentyeightyfour/. Retrieved 15 May 2020. 
  10. "Dakore Akande on IROKOtv". irokotv.com. Archived from the original on 19 May 2014. Retrieved 19 May 2014. 
  11. "Seyi Shay, Toke Makinwa, Mo’Cheddah, DJ Cuppy, Others Nominated". Pulse Nigeria. Chinedu Adiele. Retrieved 20 October 2014. 

Awọn ọna asopọ ita

àtúnṣe