Timipre Sylva
Olóṣèlú
Timipre Sylva jẹ́ ọ̀kan lára àwọn ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà. Olóṣèlú ni, ó sì ti fi ìgbà kan jẹ́ Gómìnà ni Ipinle Bayelsa. Ní ìgbà àkọ́kọ́ tí yóò jẹ gómìnà, ó g'orí òye ni ọjọ́ Kọkàndínlọ́gbọ̀n, oṣù karùn, ọdún 2007, ó sì fi ipò náà sí lẹ̀ ni ọjọ́ Kẹrìndínlógún, oṣù kẹrin ọdún 2012. Ṣáájú àkókò yìí, ó ti jẹ́ ọmọ ilé ìgbìmò aṣòfin ni ìpínlẹ̀ Rivers àná.
Timipre Sylva | |
---|---|
Governor of Bayelsa State | |
In office 29 May 2007 – 16 April 2008 | |
Asíwájú | Goodluck Jonathan |
Arọ́pò | Werinipre Seibarugo |
Governor of Bayelsa State | |
Lọ́wọ́lọ́wọ́ | |
Ó gun orí àga 27 May 2012 | |
Asíwájú | Werinipre Seibarugo |
Ìbẹ̀rẹ̀ ìgbésí ayé
àtúnṣeA bí Timipre Sylva ní ọjọ́ keje, oṣù keje, ọdún 1964[1] ní agbègbè tí à ń pè ní Brass, ní ìpínlẹ̀ Bayelsa (eléyìí tí a ti ń fi ìgbà kan pè ní ìpínlẹ̀ Riverss.
Àwọn Ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ http://bayelsa.gov.ng/government/executive/the-governor.html