Títí Adélagún Oyinsáǹ (bíi ni ọjọ́ kẹwàá oṣù kẹjọ ọdún 1985) tí orúkọ inagi rẹ jẹ TitiTheDynamite[1][2] jẹ́ agbóhùnsáfẹ́fẹ́[3] [4]ni orílẹ̀ èdè Nàìjíríà. Ó jẹ́ atọ́kun fún ètò Wake up Nàìjíríà ní ilé iṣẹ́ TVC.[5] Òun sì ní atọkun ètò Wordsmith, èyí tí wọn gbé kalẹ̀ fún àwọn ọmọdé, kí wọ́n bá lè mọ èdè gẹ̀ẹ́sì dáadáa.[6]

Titi Oyinsan
Ọjọ́ìbí10 Oṣù Kẹjọ 1985 (1985-08-10) (ọmọ ọdún 39)
Ẹ̀kọ́University of Lagos
Iṣẹ́media personality
Ìgbà iṣẹ́2002-present
Olólùfẹ́Gbemileke Oscar

Ìbẹ̀rẹ̀ pẹ̀pẹ̀ ayé àti ẹ̀kọ́ rẹ̀

àtúnṣe

Wọ́n bí Títí sì ìpínlè Èkó lórílẹ̀ èdè Nàìjíríà. Ó lọ sí orílẹ̀ èdè England nígbà tí ó sì wà ní ọmọdé, ó sì wá ní ibẹ̀ fún ọdún mẹ́wàá. Ó lọ sí ilé ẹ̀kọ́ Queen's College kí ó tó tẹ̀ ṣíwájú sí ilé ẹ̀kọ́ gíga tí University of Lagos láti kẹ́kọ̀ọ́ èdè gẹ̀ẹ́sì.

Àwọn Ìtọ́kasí

àtúnṣe