Tolu Ogunlesi jẹ́ ẹni tí a bí, nínú (Ọjọ́ kẹ̀ta, Oṣù kẹ̀ta, Ọdún 1982)[1] oníròyìn ti ìlu Nigeria ni ń ṣẹ. Ó tún jẹ́ akéwì àti ayaworan, akọ̀wé ẹ̀fẹ̀ àti Ògbóntarìgì nínú lílo ayélujára. Ogunlesi jẹ́ ẹni ti Ààrẹ Muhammadu Buhari yàn sí amúgbálẹ́gbẹ̀ẹ́ olùṣe ẹ̀rọ ayélujára titun ní ọjọ́ kejìdínlógún, oṣù kejì, Ọdún 2016.[2][3][4]

Tolu Ogunlesi
Ogunlesi in 2010
Ọjọ́ìbíTolulope Ogunlesi
3 Oṣù Kẹta 1982 (1982-03-03) (ọmọ ọdún 42)
Edinburgh, Scotland
Orílẹ̀-èdèNigerian
Ẹ̀kọ́International School Ibadan
Iléẹ̀kọ́ gíga
Iṣẹ́Journalist, writer, blogger
WebsiteÀdàkọ:Website
Ogunlesi (right) at the Halifax International Security Forum 2017

Àwọn ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. Tolu Ogunlesi CV.
  2. "Buhari appoints Tolu Ogunlesi head of new media team", Premium Times, 18 February 2016.
  3. "Buhari Appoints Tolu Ogunlesi As Special Assistant On Digital And New Media", Sahara Reporters, 18 February 2016.
  4. Muyiwa, "Popular blogger, Tolu Ogunlesi becomes Special Assistant to PMB", DotunRoy.com, 19 February 2016.