Tropidurus jẹ́ ìdílé àwọn ẹranko afàyàfà. Àwọn ẹ̀yà alángbá (ẹbí Tropiduridae) orí ilẹ̀ náà wà ní ìdíléTropidurus. Tropidurus jẹ́ ìdílé tị ọ jẹ́ ẹbí Tropiduridae, tí ó sì jẹ́ ẹbí alángbá iguanian.

Tropidurus
Tropidurus oreadicus lára ògiri ní Belém, ní Brazil
Ìṣètò onísáyẹ́nsì
Ìjọba:
Ará:
Subphylum:
Ẹgbẹ́:
Ìtò:
Suborder:
Ìdílé:
Ìbátan:
Tropidurus

Àwọn ẹ̀yà

31, see text

Synonyms
  • Platynotus
  • Strobilurus
  • Tapinurus

and see text

Àgbègbè ibi tí ó wà ati ibùgbé

àtúnṣe

A máa ń rí àwọn ẹ̀yà ìdílé Tropidurus ní òkè odò Gúúsù Amẹ́ríkà mainland, pàápàá ní igbó agijù igbóẹgàn ibi òjò Amazon àti àwọn ibi ọ̀gbẹlẹ̀

Orúkọ rẹ̀ káríayé

àtúnṣe

Kòsí orúkọ tí wọ́n mọ àwọn ẹ̀yà ìdílé Tropidurus sí. In their native range they are simply called "iguanas" as are most similar animals. If anything, the Brazilian term calango is used to particularly refer to lizards of the genus Tropidurus.

Àwọn ẹ̀yà

àtúnṣe

Àwọn ẹ̀ya wònyí ni ojúlówó tí wọ́n mọ̀ (wọ́n tò wọ́n bi ábídí).[2]

  • Tropidurus arenarius (Tschudi, 1845)
  • Tropidurus bogerti Roze, 1958
  • Tropidurus callathelys M.B. Harvey & Gutberlet, 1998
  • Tropidurus catalanensis Gudynas & Skuk, 1983
  • Tropidurus chromatops M.B. Harvey & Gutberlet, 1998
  • Tropidurus cocorobensis Rodrigues, 1987
  • Tropidurus divaricatus Rodrigues, 1987
  • Tropidurus erythrocephalus Rodrigues, 1987
  • Tropidurus etheridgei Cei, 1982
  • Tropidurus guarani Álvarez, Cei & Scolaro, 1994
  • Tropidurus helenae (Manzani & Abe, 1990)
  • Tropidurus hispidus (Spix, 1825)
  • Tropidurus hygomi J.T. Reinhardt & Lütken, 1861
  • Tropidurus insulanus Rodrigues, 1987
  • Tropidurus itambere Rodrigues, 1987
  • Tropidurus jaguaribanus Passos, Lima & Borges-Nojosa, 2011[3]
  • Tropidurus lagunablanca A.L.G. Carvalho, 2016[4]
  • Tropidurus melanopleurus Boulenger, 1902
  • Tropidurus montanus Rodrigues, 1987
  • Tropidurus mucujensis Rodrigues, 1987
  • Tropidurus nanuzae Rodrigues, 1981
  • Tropidurus oreadicus Rodrigues, 1987
  • Tropidurus pinima (Rodrigues, 1984)
  • Tropidurus psammonastes Rodrigues, Kasahara & Yonenaga-Yasuda, 1988
  • Tropidurus tarara A.L.G. Carvalho, 2016[4]
  • Tropidurus teyumirim A.L.G. Carvalho, 2016[4]
  • Tropidurus semitaeniatus (Spix, 1825)
  • Tropidurus sertanejo A.L.G. Carvalho, et al., 2016[5]
  • Tropidurus spinulosus (Cope, 1862)
  • Tropidurus torquatus (Wied-Neuwied), 1820
  • Tropidurus xanthochilus M.B. Harvey & Gutberlet, 1998

Àwọn ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. Tropidurus Integrated Taxonomic Information System (ITIS).
  2. Tropidurus The Reptile Database.
  3. Passos DC, Lima DC, Borges-Nojosa DM (2011).
  4. 4.0 4.1 4.2 Carvalho ALG (2016).
  5. Carvalho ALG et al. (2016).