Tunde Ogbeha
Gbogboogbo Nàìjíríà, Alagba ati gomina
Jonathan Tunde Ogbeha je Ogagun nibi Ise Ologun ile Naijiria to tifeyinti lati ipinle Kogi, o je olumojuto/gomina ologun fun ipinle Akwa Ibom ati leyin re fun Ipinle Bendel nigba ijoba ologun Ogagun Ibrahim Babangida (1985-1993). Leyin ti oselu pada ni 1999 o je didiboyan gege bi alagba fun Iwoorun Kogi ni Ile-igbimo Asofin Naijiria lati May 1999 titi di May 2007.
Jonathan Tunde Ogbeha | |
---|---|
Governor of Akwa Ibom State | |
In office 28 September 1987 – 30 July 1988 | |
Arọ́pò | Godwin Abbe |
Governor of Bendel State | |
In office Dec 1987 – Aug 1990 | |
Asíwájú | John Mark Inienger |
Arọ́pò | John Ewerekumoh Yeri |
Senator - Kogi West | |
In office May 1999 – May 2007 | |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọjọ́ìbí | 1947 (ọmọ ọdún 76–77) Lokoja, Kogi State, Nigeria |
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |