Turkish Abductions (tí ó túmọ̀ sí "Àwọn ìjínigbé ní orílẹ̀ èdè Turkey-àgbègbè Mediterranean nígbà náà) jẹ́ oríṣi ìkónilẹ́rú tí àwọn jàndùkú ojú omi láti àríwá ìwọ̀ oòrùn Áfíríkà ṣe ní orílẹ̀ èdè Iceland ní ìgbà oru ọdún 1627.[1]

Títa àwọn ọmọ ilẹ̀ Europe ní ọjà ẹrúAlgiers, Ottoman Algeria, 1684

Àwọn jàndùkú ojú omi náà wá láti ìlú Algiers àti Salé.[2] Wọ́n ya wọ Grindavík, East Fjords, àti Vestmannaeyjar.[1] Ènìyàn bi àádọ́ta ni wọ́n pa[1] àwọn ènìyàn irínwó ni wọ́n kó tí wọ́n sì tà ní ọkọ ẹrú.[1] Wọ́n padà san owó fún wọn ní òpò ọdún lẹ́yìn ìṣẹ̀lẹ̀ náà,[3] láti dá ènìyàn tí ó tó àádọ́ta padà.[1]

Àwọn Ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. 1.0 1.1 1.2 1.3 1.4 Þorsteinn Helgason. "Hvaða heimildir eru til um Tyrkjaránið?". Vísindavefurinn (in Èdè Icelandic). Retrieved 2020-12-06. 
  2. Þorsteinn Helgason. "Hverjir stóðu raunverulega að Tyrkjaráninu?". Vísindavefurinn (in Èdè Icelandic). Retrieved 2020-12-06. 
  3. Þorsteinn Helgason. "Hvað gerðist í Tyrkjaráninu?". Vísindavefurinn (in Èdè Icelandic). Retrieved 2019-06-10.