Uju Ugoka
Uju Ugoka Ogbodo (tí wọ́n bí ní 24 May 1993) jẹ́ agbábọ́ọ̀lù alájùsáwọ̀n ti orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, fún ẹgbẹ́ La Roche Vendée Basket Club àti Nigerian national team.[1][2] Ó gbá bọ́ọ̀lù náà fún ilé-èkọ́ rẹ̀, lábẹ́ ẹgbẹ́ Virginia Tech Hokies women's basketball.[3]
Uju Ugoka taking a foul shot at Virginia Tech in 2013 | |
No. 1 – La Roche Vendée Basket Club | |
---|---|
Position | Point guard |
League | Ligue Féminine de Basketball |
Personal information | |
Born | 24 Oṣù Kàrún 1993 Lagos, Nigeria |
Nationality | Nigerian |
Listed height | 6 ft 1 in (1.85 m) |
Listed weight | 146 lb (66 kg) |
Career information | |
College | |
NBA draft | 2014 / Undrafted |
Pro playing career | 2014–present |
Career history | |
2014-2015 | Pallacanestro Vigarano |
2015 | First Bank Basketball Club |
2015-2016 | Basket Parma |
2016-2018 | AZS-UMCS Lublin |
2018-present | La Roche Vendée Basket Club |
Iṣẹ́ tó yàn láàyò ní ilé-ẹ̀kọ́ gíga
àtúnṣeUgoka kó lọ sí United States lẹ́yìn tó ṣiṣẹ́ ní Hope for girls basketball camp, èyí tí Mobolaji Akiode dá sílẹ̀. Ó gbá bọ́ọ̀lù alájùsáwọ̀n gẹ́gẹ́ bíi ọmọ ọlọ́dún kìíní ní Grayson County College, ṣíwájú àkókò kí wọ́n tó mú ìdádúró bá gbígbá bọ́ọ̀lù alájùsáwọ̀n ní ọdún 2011, wọ́n mú u wọ ẹgbẹ́ NJCAA All-America honors.[4] Ó wá lọ sí Gulf Coast State College Commodores ní ọdún kẹta rẹ̀, pẹ̀lú ipò 16.69, 8.79 àti ìránlọ́wọ́ 0.93. Ó gba àmì-ẹ̀yẹ agbábọ́ọ̀lù tó dára jù ti NJCAA All-America honors.[5] Lẹ́yìn náà ni wọ́n gbé e lọ sí Virginia Tech Hokies women's basketball ní ọdún 2012 fún ẹ̀kọ́ ọlọ́dún kékeré àti ọlọ́dún àgbà.[6] Lásìkò tó wà ní ọdún kékeré, ó gba ipò 12.5 àti àtúnṣe 8.5.[7] Ní ọdún àgbà rẹ̀, ó gba ipò 18.4, àtúnṣe 9.6 àti ìrànlọ́wọ́ fún ayò kọ̀ọ̀kan.[8][9]
Iṣẹ́ rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí i agbábọ́ọ̀lù fún orílẹ̀-èdè
àtúnṣeẸgbẹ́ kékeré
àtúnṣeUgoka ṣojú Nàìjíríà ní 2008 FIBA Africa Under-18 Championship for Women níbi tí ó ti gba ipò 3 points àti àtúnṣe 3.[10][11]
Ẹgbẹ́ àgbà
àtúnṣeUgoka ṣojú Nàìjíríà bákan náà 2009 FIBA Africa Championship for Women, níbi tí ó to gba 7 points, àti àtúnṣe 3.2 pẹ̀lú ìrànlọ́wọ́ 0.5 nínú ayò kọ̀ọ̀kan.[12] Ní 2009 FIBA Africa Championship for Women, ó gba 7.4 points, àtúnṣe 5.1 àti ìrànlọ́wọ́ 0.3 nínú ayò kọ̀ọ̀kan.[13] Ugoka tún ṣojú Nigerian national team ní 2016 FIBA World Olympic Qualifying Tournament for Women tó wáyé ní France, ó gba 5 points, àtúnṣe 5 àti ìrànlọ́wọ́ 1 nínú ayò kọ̀ọ̀kan.[14][15]
Àwọn ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ "Uju Ugoka". fiba.basketball.
- ↑ "Uju Ugoka". fiba.basketball.
- ↑ Minichino, Adam. "Uju Ugoka turning hope into reality". espn.com. https://www.espn.com/espnw/athletes-life/story/_/id/10296843/hokie-uju-ugoka-living-life-long-dream-espnw.
- ↑ bakiode. "UJU UGOKA TURNING HOPE INTO REALITY". hope4girlsafrica.com.
- ↑ "WOMEN'S BASKETBALL". njcaa.com.
- ↑ "Alyssa Thomas scores 26 points, adds 18 boards in Maryland rout". espn.com. https://www.espn.com/womens-college-basketball/recap?gameId=330130259.
- ↑ "UJU UGOKA". hokiesports.com.
- ↑ "Uju Ugoka". sports.yahoo.com.
- ↑ Minichino, Adam. "Uju Ugoka turning hope into reality". espn.com. https://www.espn.com/espnw/athletes-life/story/_/id/10296843/hokie-uju-ugoka-living-life-long-dream-espnw.
- ↑ "Uju Ugoka's profile". archive.fiba.com.
- ↑ Akinbo, Peter (2023-09-07). "Why I dumped goalkeeping for basketball -- Ugoka". Punch Newspapers (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2023-09-08.
- ↑ "Uju Ugoka's profile". archive.fiba.com.
- ↑ "Uju Ugoka's profile 2009 FIBA Africa Champions Cup for Women". archive.fiba.com.
- ↑ "2016 FIBA Women 's Olympic Qualifying Tournament". archive.fiba.com.
- ↑ "Uju Ugoka". fiba.basketball.