Ulunma Jerome jẹ agbábọ́ọ̀lù obìnrin órilẹ èdè Nàìjíríà tí a bí ní ọjọ́ kọkànlá oṣù kẹrin ọdún 1988. Ó n gbá bọ́ọ̀lù jẹun gẹ́gẹ́ bí adilémú lọ́wọ́bẹ̀yìn fún ikọ̀ agbábọ́ọ̀lù Pitea tí ó wà ní Sweden Damallsvenskan[1][2][3].

Ulunma Jerome
Personal information
OrúkọUlunma Jerome
Ọjọ́ ìbí11 Oṣù Kẹrin 1988 (1988-04-11) (ọmọ ọdún 36)
Ibi ọjọ́ibíMbieri, Nigeria
Ìga1.60 m (5 ft 3 in)
Playing positionDefender
Club information
Current clubPiteå IF ladies team
Senior career*
YearsTeamApps(Gls)
2007–2009Rivers Angels
2010–Piteå IF ladies team26(0)
* Senior club appearances and goals counted for the domestic league only.
† Appearances (Goals).

Àṣeyọri

àtúnṣe
  • Ulunma ti kopa ninu óriṣiriṣi ere idije fun team awọn obinrin ti national lori bọọlu[4][5]

Itọkasi

àtúnṣe
  1. https://ng.soccerway.com/players/ulumma-jerome/19459/
  2. https://fbref.com/en/players/4bfc359f/Ulunma-Jerome
  3. https://www.olympedia.org/athletes/111251
  4. https://www.worldfootball.net/player_summary/ulunma-jerome/
  5. https://www.fifa.com/en/tournaments/womens/womensolympic/beijing2008/teams/1882893