Umar Sani (ọjọ́ karùn-úndínlọ́gbọ̀n, oṣù Ṣẹrẹ, ọdún 1963 ní wọ́n bí i) jẹ́ olùdámọ̀ràn àgbà lórí ìròyìn àti ìpolongo sí igbákejì olórí orílẹ̀-èdè Nàìjíríà Namadi Sambo[2][3] . Ó ti jẹ́ olùrànlọ́wọ́ sí Sambo's láti ọdún 2007 nígbà tí Sambo jáwé olúborí nínú ìdìbò gómìnà ní ìpínlè Kaduna. Ó wà lára àwọn tí wọ́n tí wọ́n polongo fún ẹgbẹ́ òṣaèlú PDP ní ọdún 2019. Tí ó sì dúró gẹ́gẹ́ bí agbẹnusọ, bẹ́ẹ̀ náà ni ó jẹ́ ọmọ ẹgbẹ́ PDP fún ìgbà pípẹ́.

Umar Sani
Ọjọ́ìbíUmar Sani
25 Oṣù Kínní 1963 (1963-01-25) (ọmọ ọdún 61)
Kaduna, Kaduna State, Nigeria
Iṣẹ́Media & Public Affairs
OfficeSenior Special Adviser, Media & Publicity to the Nigerian Vice President, Namadi Sambo
Political partyPDP
Olólùfẹ́
Hajiya Sahura Umar Tijjani
(died 2013)
[1]
Àwọn ọmọ4

Iṣẹ́

àtúnṣe

Umar Sani bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ rẹ̀ gẹ́gẹ́ olùkọ́ nígbà tí iṣẹ́ olùkọ́ ṣì wá fún àwọn tó bá ṣe dáadáa nínú ẹ̀kọ́ won nìkan. Leyin tí ó ẹ́kọ̀ọ́ gboyè ní Kagoro Teachers College in ìbẹ̀rẹ̀ 1980, ni ìpínlẹ̀ Kaduna ó gba iṣẹ́ sí ẹ̀ka ẹ̀kọ́ Local Education Department ti ìpínlẹ̀ Kaduna gẹ́gẹ́ bí olùkọ̀ọ́ ìyàrá ìkàwé. Lẹ́yìn náà ó fi iṣẹ́ sílẹ̀, ó sì wọlé sí ilé-ẹ̀kọ́ gíga pólì ti Kaduna, ní ìpínlè Kaduna ibi tí ó ti gba ìwé-ẹ̀rí dípílómà nínú kárà-kátà.

Àwọn ìtọ́kasí.

àtúnṣe
  1. Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid <ref> tag; no text was provided for refs named promptnews.2013.06.13
  2. "Sambo's brother dies in Abuja auto crash". Archived from the original on 2014-04-28.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  3. "Group accuses Sambo of margnalising North East, North Central | Premium Times Nigeria". 10 September 2013.