Umshana
Umshana ni eré ti ọdún 2015 kan tí wọ́n ṣe lórílẹ̀-èdè Eswatini tí olùdarí rẹ̀ n ṣe Bi Phakathi, èyí tí ilé-iṣé BIP Films ṣètò àgbéjáde rẹ̀.[1] Àwọn olùkópa eré náà pẹ̀lú Mbali Dlamini, Delani Dlamini, Lisa Mavuso, Temakhosi Nkambule àti Fineboy Mhlanga.[2][3]
Umshana | |
---|---|
Adarí | Bi Phakathi |
Òǹkọ̀wé | Bi Phakathi |
Ìyàwòrán sinimá | Sandile Simelane |
Ilé-iṣẹ́ fíìmù | BIP Films |
Déètì àgbéjáde | 25 November 2015 (Swaziland) |
Àkókò | 51 min. |
Orílẹ̀-èdè | Swaziland |
Èdè | Siswati |
Èyí ni àkọ́kọ́ fíìmù tí wọ́n máa ṣe lédè Swati. Gbogbo ṣíṣe eré náà síì wáyé ní orílẹ̀-èdè Eswatini.[4]
Àwọn olùkópa
àtúnṣe- Mbali Dlamini as Gugu
- Delani Dlamini as Themba
- Lisa Mavuso as Gugu's Friend
- Temakhosi Nkambule as Precious
- Fineboy Mhlanga as Uncle
Àwọn ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ "Umshana (2015)". filmaffinity. Retrieved 20 October 2020.
- ↑ "Umshana (2015)". cinematerial. Retrieved 20 October 2020.
- ↑ "Umshana (2015)". yeclo. Retrieved 20 October 2020.[Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́]
- ↑ "The Niece 2015 'Umshana' Directed by Bi Phakathi". letterboxd. Retrieved 20 October 2020.