Villeneuve-d'Ascq
- Villeneuve-d'Ascq wa ni ipoidojuko 50°37′10″N 3°07′54″E / 50.619489°N 3.131765°ECoordinates: 50°37′10″N 3°07′54″E / 50.619489°N 3.131765°E
Villeneuve-d'Ascq (ìpè Faransé: [vil.nœv.dask]) jẹ́ ìlú tuntun, èyí tá a dá 1970 ní apá àríwá Fránsì. Agbègbè náà tóbi tó 27.46 km², tí àwọn ènìyàn inú rẹ̀ sí jẹ́ 62,616 nígbà ìkànìyàn ọdún 2013.