Waagashi jẹ́ irú wàrà jíjẹ ní Ìwọ̀òrùn Áfíríkà tí a fi mílíkì màálù ṣe. Àwọn Fúlàní pàápàá àwọn ti apá Àríwá Benin ni wọ́n máa ń ṣe é.[1] Ó jẹ́ títà lọ́pọ̀ yanturu ní Parakou, ìlú kan ní àárín gbùngbùn Benin.[2]

Waagashi

Ìlànà Sísè

àtúnṣe

Tí mílíkì màálù bá ti gbóná. Fi ewé "fromagier" (ewé tí a tún mọ̀ sí Bombax ceiba). Mílíkì náà á bẹ̀rẹ̀ sí ní jàn pọ̀, lẹ́yìn náà ni a máa wá yọ èyí tó ti jàn pọ̀ kúrò tí a ó sì tẹ àwọn mílìkì tó jàn pọ̀ náà papọ̀. Lẹ́yìn náà ni a máa fi sínú òrí pupa tí a fi ewé mìíràn ṣe láti lè paá mọ́ fún ìgbà pípẹ́.

Àwọn Ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. Theresa (2010-05-22). "Cutting the cheese in Benin". SubjectVerbObject (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2020-06-06. 
  2. "Parakou". Benintourism.com. Retrieved January 10, 2009.