won bi Oloye Wahab (Abdulwahab) Iyanda Folawiyo
 ni June 16, 1928 , o ku ni  June 6, 2008. o je onisowo omo orile ede Naijiria ti o si je oluran-lowo fun awon eniyan.[1] Ni odun 1957, O da ile ise Yinka Folawiyo & Sons kale, eyi ti  o je ipile fun awon ogooro ile ise ree to ku.[2][3] Won bi iyanda Wahab Folawiyo ni ipinle Eko si idile Pa Tijani, eni ti o je onisowo pelu, lasiko ijoba amunisin (British colonial era). O lo si ile eko agba ti University of North London ni odun 1951, nibi ti o ti gba oye imo nipa eto imojuto ile ise (Management), ti o si duro lori (Ship Brokerage). O pada sile lati bere ile ise Yinka Folawiyo & Sons, ti o da lori rira lati ati tita oja si oke Okun  (import and export business). Folawiyo tun je eni akoko ti fun Baltic Exchange in London.

Abdulwahab Iyanda Folawiyo
Ọjọ́ìbí(1928-06-16)16 Oṣù Kẹfà 1928
Lagos, Nigeria
Aláìsí6 June 2008(2008-06-06) (ọmọ ọdún 80)
Orílẹ̀-èdèNigerian
Ẹ̀kọ́Management
Iléẹ̀kọ́ gígaUniversity of North London
Iṣẹ́Founder, Yinka Folawiyo Group Nigeria Limited
Àwọn ọmọTunde Folawiyo (son)
Àwọn olùbátanLisa Folawiyo (daughter-in-law)

Iwa iranilowo re

àtúnṣe

Gege bi oluran-lowo awon alaini, o kopa ninu orisirisi idagbasoke awujo ati esin paa paa julo esin (Islam). O ko oniruuru mosalasi kaakiri orile ede Naijiria, ti o fi mo Lagos Central ati Surulere Central mosques ni ipinle Eko pelu   Mosalasi Sultan Bello ni Kaduna. O tun fi ile awon omo alaini ti (Bab Es Salam Home for orphans in Lagos).[4]

Ni tere idaraya, O tun je oluran-lowo fun (Yinka Folawiyo U 15 Athletics Championships and the National Amateur Wrestling Championships). Nipa eto eko, o ra opolopo ojulowo aga ijoko fun iyara iwadi ni ile eko agba ti University of Lagos, o tun da si imo iwadi arun kokoro ajenirun ni ile eko agba ti University of Ibadan. Ni odun 1988,,Folawiyo di eni akoko ti o ko ile kan si ile eko agba ri ipinle Eko (University of Lagos) gege bi aladani akoko ti yoo ko ile iwosan  alabode ti o si soo di ile iwosan to nla fun ile eko naa ti won si n ya aworan  X-ray Unit nibe.[citation needed]

Oloye Wahab di ara ile ni kutu kutu ojo Kefa,osu Kefa ofun 2008 (June 6, 2008), ni ile re ti o wa ni Queens Drive, Ikoyi, ni ipinle Eko, nigba ti o di omo odun  metadin-laadorin (79) nigba ti o n reti lati se ayeye ojo ibi aadorin odun laipe. Won si Iyanda ni ilana Musulumi, ni ojo naa ni deede agogo maruun ku iseju meedogunon ( 4:45 p.m.) ni ite nla ti won ma n sin awon asaaju esin Musulumi si. Awon meji pere ni won ti sin si ite naa saaju Folawiyo, awon naa ni Imam Ibrahim Otun and Imam Murah. Awon laami laaka lorile ede Naijiria da giiri lati seye ikeyin fun oloogbe naa lara won ni olori orile ede Naijiria igba naa Aare Olusegun Obasanjo ati igbakeji re Atiku Abubakar, ti awon gomina  gomina ko lo n ka lati ba awon ebi re kedun.[citation needed]

Awon ami eye to ti gba

àtúnṣe
  • Doctor of Law by the University of Cross River State, Uyo, 1991,
  • Doctor of Letters by Ahmadu Bello University, Zaria, 1992
  • Doctor of Science by the Lagos State University, Ojo, Lagos, 1998
  • key to Dade County, Florida, in the U.S.
  • Millennium Award of Doctor of Science, University of Lagos

Awon oye ti won fi je

àtúnṣe
  • Baba Adini of Nigeria, a chieftaincy title[5]
  • Grand Patron of Nigerian Muslim Council
  • Chairman, Executive Council of the Lagos Central Mosque
  • Honorary Fellow, Chartered Institute of Transport
  • Fellow of the Commonwealth Journalists Association
  • Chairman, Maize Association of Nigeria and Patron
  • Institute of Freight Forwarders of Nigeria
  • Order of Federal Republic, OFR, conferred on him in 1982
  • Commander of the Order of the Niger, CON, on Nov. 16, 2000.
  • Chancellor, Lagos State University on April 17, 1999.
  • Patron of the Nigerian British Chamber Diyabet Cerrahisi

Awon itoka si

àtúnṣe