Wale Adenuga

(Àtúnjúwe láti Wale adenuga)

Wale Adenuga jẹ ẹni tí àbí bi ọjọ kerinlelogun osu kẹsan odun 1950 ( 24 September 1950) òjé ọmọ orilẹ ede Naijiria, awọn iṣẹ ti oti se séyìn níí, Iṣẹ Alaworan éfé, iṣẹ akede, ati iṣẹ adari èrè òṣèré. Iṣẹ ti òun ṣe lọwọ lọwọ níí iṣẹ adari èrè orí itage, òjé gbajugbaja ní awọn iṣẹ wọnyii ti amo káàkiri àgbáyé bí àwọn isẹ bíi, Ikebe Super, Binta and Friends ati Super Story, wọn sìn bẹ ni ori tẹlifisiọnu tí WAP tv darí rẹ.[2]

Wale Adenuga
MFR
Ọjọ́ìbíWale Adenuga
24 Oṣù Kẹ̀sán 1950 (1950-09-24) (ọmọ ọdún 74)
Ẹ̀kọ́University of Lagos
Iṣẹ́Cartoonist
Publisher
Producer
Notable workSuper Story
Papa Ajasco
Olólùfẹ́
Ehiwenma Adenuga (m. 1975)
[1]

Àwọn ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid <ref> tag; no text was provided for refs named myhubby
  2. Kasali, Segun (2021-10-30). "Nigerians are natural actors — Wale Adenuga MFR". Nigerian Tribune. https://tribuneonlineng.com/nigerians-are-natural-actors-wale-adenuga-mfr/.