Walter Benjamin
Walter Bendix Schönflies Benjamin (Pípè nì Jẹ́mánì: [ˈvalter ˈbenjamiːn], 15 July 1892 – 27 September 1940) je omowe omo Ju Jemani, to sese orisirisi bi olugbewo onimookomooka, amoye, aseoro-awujo, ayiededa, olukede redio ati alaroko.
Walter Benjamin | |
---|---|
Orúkọ | Walter Benjamin |
Ìbí | Berlin, German Empire | 15 Oṣù Keje 1892
Aláìsí | 27 September 1940 Portbou, Catalonia, Spain | (ọmọ ọdún 48)
Ìgbà | 20th-century philosophy |
Agbègbè | Western Philosophers |
Ẹ̀ka-ẹ̀kọ́ | Western Marxism, Frankfurt School |
Ìjẹlógún gangan | Literary theory, Aesthetics, Technology, Epistemology, Philosophy of language, Philosophy of history |
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |