Wana Udobang
Wana Udobang, tí a tún mọ̀ sí Wana Wana, jẹ́ Akọ̀ròyìn orile-èdè Nàìjíríà, ó tún jẹ́ akéwì, oníròyìn, òṣèré àti òṣìṣé amóhùnmáwòran.[1] Iṣé rẹ̀ ti hàn ní orí BBC,[2] Al Jazeera, Huffington Post, BellaNaija, àti The Guardian,[3] Wọ́n ṣe àpèjúwe rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí i "ọ̀kan lára àwọn tó dáátọ́ lẹ́nu kí á sọ̀rọ̀ tó múná dóko."[4]
Wana Udobang | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | Lagos, Nigeria |
Orílẹ̀-èdè | Nigerian |
Orúkọ míràn | Wana Wana |
Iṣẹ́ | Poet, broadcaster, journalist |
Website | wanawana.net |
Àwọn Ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ Onyemaechi, Ijeoma (27 June 2017). "I may one day go back to being a radio presenter, says Wana Udobang". TheCable Lifestyle. https://lifestyle.thecable.ng/wana-udobang-radio-poet-oap/.
- ↑ "Writing a New Nigeria – Episode guide – BBC Radio 4". BBC. Retrieved 23 November 2017.
- ↑ Udobang, Wana (21 February 2017). "'The exorcism was over in 15 minutes but nothing changed' – LGBT life in Nigeria". The Guardian. ISSN 0261-3077. https://www.theguardian.com/global-development-professionals-network/2017/feb/21/from-exorcism-to-acceptance-lgbt-life-in-nigeria.
- ↑ Okolo, Edwin (5 September 2017). "Essentials: Wana Udobang's 'In Memory Of Forgetting' is not a feminist album, it is so much more". The Native. http://thenativemag.com/music/wana-udobang-in-memory-of-forgetting/.