Wazobia FM Eko
Wazobia 95.1 FM Lagos jẹ́ ìkànnì agbóhùn sáfẹ́fẹ́ àdàmọ̀dì-Gẹ̀ẹ́sì Nàìjíríà ní ìpínlẹ̀ Èkó. A dá sílẹ̀ ní ọdún 2007, ó jẹ́ ti Globe communication Limited.
Wazobia Fm Lagos jẹ́ mímọ̀ fún ọ̀nà ìpanilẹ́rìn ín láti gbóhùn sáfẹ́fẹ́ . Ìkànnì náà máa ń gbé ètò bí i ìròyìn, orin, eré-ìdárayá, ìfọ̀rọ̀wánilẹ́nuwò, ọ̀rọ̀ tó ń lọ sáfẹ́fẹ́.
.
"Owogram.com" fi Wazobia Fm Lagos sí ìpó kínní nínú àwọn ìkànnì agbóhùn sáfẹ́fẹ́ mẹ́wàá tí ó dára jùlọ ní ìpínlẹ̀ Èkó, ó fi kun pé "ó jẹ́ ìkànnì agbóhùn sáfẹ́fẹ́ tó jẹ́ ààyò tí ọ̀pọ̀lọpọ̀ ọmọ Nàìjíríà máa ń kàn sí pàápàá ní Èkó. Ó jẹ́ ìkànnì agbóhùn sáfẹ́fẹ́ àdàmọ̀dì-Gẹ̀ẹ́sì àkọ́kọ́ ní Nàìjíríà tí ó sì máa ṣe ètò ni èdè àdàmọ̀dì-Gẹ̀ẹ́sì, tí onírúurú ènìyàn sì máa ń gbàdùn. Gbogbo ènìyàn ni ó máa ń gbàdùn rẹ̀.
"Alternative Adverts" ṣe akojọ ile-iṣẹ redio naa gẹgẹbi nọmba akọkọ ninu atokọ 10 ti o ga julọ ti awọn ile-iṣẹ redio ti o ṣabẹwo julọ ni Ipinle Eko, ọdun 2019. Wọn tun fi kun pe “Wazobia FM ni awọn mejeeji n gbọ ati igbadun nipasẹ gbogbo awọn ẹka eniyan; awakọ ọkọ akero, awọn oṣiṣẹ, awọn ọmọ ile-iwe, awọn obinrin ọja, ati bẹbẹ lọ. O jẹ ibudo itunu fun gbogbo eniyan."