We Could Be Heroes
We Could Be Heroes jẹ́ eré ìlú Morocco tí a ṣe àgbéjáde rẹ̀ ní ọdún 2018. Ó jẹ́ fíìmù tí ó dá lórí eré ìdárayá èyí tí Hind Bensari Hind Bensari darí, tí Habib Attia [[Habib Attia] àti Vibeke Vogel sì ṣe àgbéjáde rẹ̀ fún ilé iṣẹ́ fíìmù tí Bullitt. Moroccan [1] Fíìmù náà dá lórí ayé tí Azedinne Nouiri [Azeddine Nouiri], tó jẹ́ olúborí tí Paralympic shot-put, tó borí àwọn ìpèníjà tí ara tó ní láti di ẹni tí a yàn sí 2016 Rio Paralympic Games pẹ̀lú ọ̀rẹ́ ìgbà èwe rẹ̀ Youssef.[2]
We Could Be Heroes | |
---|---|
Adarí | Hind Bensari |
Olùgbékalẹ̀ | Bullitt Films |
Òǹkọ̀wé | Hind Bensari |
Àwọn òṣèré | Azeddine Nouiri |
Orin | Tin Soheili |
Ìyàwòrán sinimá | Sofie Steenberger |
Olóòtú | Lilia Sellami |
Ilé-iṣẹ́ fíìmù | Cinetele Films |
Déètì àgbéjáde |
|
Àkókò | 79 minutes |
Orílẹ̀-èdè | Morocco |
Èdè | Arabic |
Ìṣèfihàn àkọ́kọ́ ti fíìmù náà wáyé ní ọjọ́ kejì, oṣù karùn-ún ọdún 2018 ní tíátà ti Scotiabank.[3] Fíìmù náà gbà àtúngbéyẹ̀wò tí ó dára àti ọ̀pọ̀ àmì ẹ̀yẹ ní àwọn ayẹyẹ tí fíìmù ní àgbáyé.[4][5]
Fíìmù náà gbà àmì ẹ̀yẹ tí Júrì ní Hot Docs Canadian International Documentary Festival. Fíìmù náà tún gbà àmì ẹ̀yẹ àkọsílẹ̀ tí àgbáyé tó dáa jù ní ayẹyẹ fíìmù àgbáyé ní Toronto.[6] Fíìmù náà gbà àmì ẹ̀yẹ ti Grand Prix ní Sinimá Morocco, ibi ayẹyẹ Tangier.[7]
Àwọn ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ "475: Break the Silence". Indiegogo. Retrieved 10 October 2020.
- ↑ "We Could Be Heroes". DFI. Retrieved 10 October 2020.
- ↑ "Hot Docs 2018: Our Review of 'We Could Be Heroes'". intheseats. Archived from the original on 23 October 2020. Retrieved 10 October 2020.
- ↑ "We Could Be Heroes 2018 Directed by Hind Bensari". letterboxd. Retrieved 10 October 2020.
- ↑ "We Could Be Heroes". hotdocs. Retrieved 10 October 2020.
- ↑ "Hind Bensari: Director". festivalmarrakech. Archived from the original on 23 October 2020. Retrieved 8 October 2020.
- ↑ "We could be Heroes says Hind Bensari". Next Century Foundation. Retrieved 8 October 2020.