Ilé Ìfowópamọ́ Wema jẹ́ ọ̀kan nínú àwọn ilé Ìfowópamọ́ tó dáńgájíá jùlọ tí Ìjọba Àpapọ̀ Orílẹ̀ èdè Nàìjíríà fún ní ìwé àṣẹ láti le ṣiṣẹ́ lórílẹ̀ èdè Nàìjíríà. Pàràkòyí oníṣòwò ajé ọjọ́un, Oloye Adékọ̀yà Òkúpè Agbọ́nmágbẹ ló dáa sílẹ̀ lọ́dún 1945. Agbọ́nmágbẹ Bank ní orúkọ tí ó sọ ọ́ nígbà náà, ṣùgbọ́n àyípadà àti àtúnṣe ló sọ ọ́ di Wema Bank. [2] [3] [4] [5] [6]

Wema Bank Plc.
TypePublic
NSE :WEMABANK
Founded2 May 1945
Headquarters54 Marina, Lagos Island Lagos State, Nigeria
Key peopleAdemola Adebise, Managing Director/Chief executive officer;
Babatunde Kasali, Chairperson
IndustryFinancial services
ProductsRetail banking, Commercial Banking, Corporate banking
ServicesBanking
Total assets₦ 421bn (2016)[1]
Employees1,317
Websitewemabank.com
Àwòrán ìdánimọ̀ ilé ìfowópamọ́ Wema

Àwọn Ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. "Wema Bank Audited Financials 2012" (PDF). Archived from the original (PDF) on 2013-12-03. Retrieved 2020-01-08. 
  2. Salako, Femi (2018-03-22). "Tribute to a doyen of patriotism – Daily Trust". Daily Trust. Archived from the original on 2018-03-22. Retrieved 2020-01-08. 
  3. "Our History". Wemabank. 2017-12-14. Retrieved 2020-01-08. 
  4. "Okupe faults Subomi Balogun’s claims of being first indigenous banker - Vanguard News". Vanguard News. 2018-01-13. Retrieved 2020-01-08. 
  5. "3PLR – AGBONMAGBE BANK LTD V. C.F.A.O. – Judgements". Judgements – Law Nigeria. 2018-06-13. Retrieved 2020-01-08. 
  6. "Indigenous Banks in Colonial Nigeria on JSTOR". JSTOR. Retrieved 2020-01-08.