Dame Wendy Margaret Hiller ni a bini ọjọ karun dilogun óṣu August ni ọdun 1912 ti o si ku ni ọjọ kẹfa dilogun óṣu May ni ọdun 2003 (15 August 1912 – 14 May 2003) jẹ óṣèrè óritage èdè gẹẹsi ti o si tin ba iṣẹ naa bọ lati ọgọta ọdun. Wendy duró gẹgẹbi óṣèrè oritage pẹlu gbogbo akitiyan rẹ ninu siṣè ere[1][2].

Wendy Hiller
Hiller in Sailor of the King (1953)
Ọjọ́ìbíWendy Margaret Hiller
(1912-08-15)15 Oṣù Kẹjọ 1912
Hazel Grove and Bramhall Urban District
Aláìsí14 May 2003(2003-05-14) (ọmọ ọdún 90)
Beaconsfield, Buckinghamshire, England
Resting placeSt Mary Churchyard, Radnage, Buckinghamshire, England
Iṣẹ́Actress
Ìgbà iṣẹ́1935–1993
Olólùfẹ́
Ronald Gow
(m. 1937; died 1993)

Igbesi Aye Obinrin naa

àtúnṣe

Wendy ni a bisi ilẹ Bramhall ti o si jẹ ọmọbinrin Frank Watkin Hiller ati Marie Stone. Óṣèrè naa kẹkọ ni Ilè ẹkọ Ilè Winceby, nigba ti arabinrin naa pẹ ọmọ ọdun mejidinlogun ódarapọ mọ Ilè iṣẹ Repertory Manchester nibi ti o ti ṣè ere fun ọdun pipẹ[3]. Joel Hirschorn ṣe apejuwe wendy gẹgẹbi óṣèrè lobinrin ti o gba gbẹrẹ ti o si ma duró bi akinkanju ninu awọn èrè rẹ. Ni ọdun 1937, Wendy fẹ akọ ere kalẹ Ronald Gow ti o jẹ senior rẹ fun ọdun ọdun marun dilogun ti wọn si jọ tọ awọn ọmọ meji Ann ati Anthony ni ilẹ ti oun jẹ Spindles[4].

Ami Ẹyẹ ati Idanilọ lọla

àtúnṣe

Wendy je osere to gba Ebun Akademi bi Obinrin Osere Keji Didarajulo. Ni ọdun 1959, Wendy gba Oscar ninu ere Seperate Tables nibi ti o jẹ óludari hotel ati Misitrẹẹsi ti Burt Lancaster[5][6]. Ni ọdun 1975. arabinrin naa jẹ Apaṣẹ Dame. Ni ọdun 1984, Arabinrin naa gba ami ẹyẹ doctorate lati Ilè iwe giga manchester[7]. Ni ọdun 1996, Ere critics circle ti ilu london da Hiller lọla Ami ẹyẹ Dilys Powell fun akitiyan rẹ ni ere ilẹ british.