Agbègbè Apáìwọ̀òrùn Nàìjíríà

(Àtúnjúwe láti Western Region, Nigeria)

Agbègbè Apaiwóòrun Orílé èdè Nàìjíríà tabi Western Region fi igba kan je apa iselu ijoba orile-ede Naijiria pelu oluilu ni Ibadan. Won da sile ni odun 1930 labe ijoba awon ara Britani, o si wa titi di odun 1967.

Maapu Agbègbè Apáìwọ̀òrùn Nàìjíríà ni 1965


Àyọkà tóbáramuÀtúnṣe


ItokasiÀtúnṣe