What Just Happened (fiimu 2018)

What Just Happened is je fiimu apanilerin ti odun 2018 lati Naijiria ti Charles Uwagbai daari, Ufuoma McDermott, Afeez Oyetoro, Segun Arinze, Toyin Abraham, Mike Ezuruonye peelu awon osere apanilerin Mc Abbey ati Funny Bone koopa ninu. [1] [2] Ufuoma McDermott lo se agbejade ati kiko fiimu naa. [3] Ipinlẹ Eko ati Los Angeles ni wọn ti ya fiimu naa.

Ahunpo Itan

àtúnṣe

Ọ̀mowe Oghogho (Ufuoma McDermott) tí oni inú bibàjẹ́, pinnu láti padà sílé láti orílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà láti lọ gba ipò olùkọ́ àbẹ̀wò ní Yunifásítì ti Ìbàdàn, ìpínlẹ̀ Ọyọ̀ tí ẹ̀gbọ́n rẹ̀ Efe (Segun Arinze) dámọ̀ràn lẹ́yìn tí ó pinnu pé orílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà ti su oun ati pe kori ololufe niibe.

Ati ri bi nkan se je le fun nitori iwa igberaga re. Nigbati awako re- Baba Oti (Afeez Oyetoro) munu bi pelu iko alaiduro re ,o pinnu lati wakọ naa funrarẹ lati Eko losi Ibadan. Irin-ajo tiko ju wakati kan lo di ọjọ kan ti isinwin ati ariwo bi o jẹ ki irin ajo na di iti ko fararo.

Gbogbo fiimu naa jẹ itan kan laarin itan mi, bi Ojogbon Oghogho ṣe n sọ gbogbo ipade gẹgẹbi ẹri ninu ile ijọsin,[4] nitori pe kosi akoko pupo, igbiyanju lati mu ẹri rẹ yara tun da ikolu siile.

Awon Osere

àtúnṣe

Ṣiṣejade

àtúnṣe

Leyin aseyori ere sinima akoko re Christmas is Coming ni odun 2017, afiihan ere wo sinima ni ojo kerila Osu keesan odun 2018.[5] Fọtoyiya akọkọ ti bẹrẹ ni Oṣu Karun ọdun 2015 ni Ilu Eko ati Los Angeles, lakoko ti Ufuoma ti loyun. [6] Lẹhin igba ti obimo rẹ ni Oṣu Kẹjọ Ọjọ kejo, Ọdun 2015, iṣelọpọ tẹsiwaju ni ọdun 2016 ati iṣelọpọ igbeyin pari ni aarin ọdun 2018.

Iwe Iroyin Vanguard ṣe afihan ere apanilẹrin akọkọ ti oṣere Ufuoma Mcdermott peelu oriyin, o sọ pe “...lẹyin ti a ri 'What just happened', oju mi si si nkan tuntun nipa rẹ; pupọ julọ si agbara rẹ kii ṣe gẹgẹ bi eniyan nikan, ṣugbọn gẹgẹbi oṣere paapaa. ", sibẹsibẹ won ṣe akiyesi pe "... ipa rẹ ninu fiimu naa gege bi apanilẹrin le jasofo laisi ifarahan ọkan ninu awọn talenti ti o ni imọran julọ ni ile-iṣẹ fiimu Naijiria, Toyin Abraham." [7]

Awọn itọkasi

àtúnṣe
  1. "Ufuoma McDermott's next movie is a comedy starring Segun Arinze, Toyin Aimakhu, Mike Ezuruonye". The PulseNg (Lagos, Nigeria). 9 August 2018. Archived from the original on 10 August 2018. https://web.archive.org/web/20180810113056/https://www.pulse.ng/entertainment/movies/meet-the-cast-of-ufuoma-mcdermotts-what-just-happened-id8707225.html. Retrieved 22 September 2018. 
  2. "Ufuoma Mcdermott’s new movie ‘What Just Happened’ hits cinemas". Vanguard Newspaper (Lagos, Nigeria). 15 September 2018. https://www.vanguardngr.com/2018/09/ufuoma-mcdermotts-new-movie-what-just-happened-hits-cinemas/. Retrieved 22 September 2018. 
  3. "Toyin Abraham, Funny Bone, Ufuoma Mcdermott take ‘What Just Happened’ to the cinemas". Sahara Weekly Newspaper (Lagos, Nigeria). 15 September 2018. https://www.saharaweeklyng.com/toyin-abraham-funny-bone-ufuoma-mcdermott-take-just-happened-cinemas/. Retrieved 22 September 2018. 
  4. "Ufuoma Mcdermott’s movie, ‘What Just Happened’ for cinemas September 14". The Nation Newspaper (Lagos, Nigeria). 15 September 2018. http://thenationonlineng.net/ufuoma-mcdermotts-movie-what-just-happened-for-cinemas-september-14/. Retrieved 2 October 2018. 
  5. "Ufuoma Mcdermott’s What Just Happened hits Cinemas". Daily Tribune Newspaper (Lagos, Nigeria). 16 September 2018. Archived from the original on 16 September 2018. https://web.archive.org/web/20180916130726/https://www.tribuneonlineng.com/164589/. Retrieved 22 September 2018. 
  6. "Ufuoma Mcdermott’s What Just Happened is in Cinemas". Guardian Newspaper (Lagos, Nigeria). 16 September 2018. Archived from the original on 30 October 2020. https://web.archive.org/web/20201030173217/https://guardian.ng/saturday-magazine/ufuoma-mcdermotts-what-just-happened-is-in-cinemas/. Retrieved 26 September 2018. 
  7. "Movie Review: What Just Happened". Vanguard Newspaper (Lagos, Nigeria). 29 September 2018. https://www.vanguardngr.com/2018/09/movie-review-what-just-happened/. Retrieved 12 November 2018. 