Tóyìn Abraham
Toyin Abraham[3] tàbí Olutoyin Aimakhu; ni wọ́n bí ní (September 5, 1984). Ó jẹ́ òṣèré orí ìtàgé , olùgbéré-jáde àti adarí eré, ọmọ rílẹ̀-èdè Nàìjíríà.[4][5][6][7]
Toyin Abraham | |
---|---|
Toyin Abraham at AMVCA 2020 | |
Ọjọ́ìbí | 5 Oṣù Kẹ̀sán 1980 Auchi, Edo, Nigeria |
Orílẹ̀-èdè | Nigerian |
Ọmọ orílẹ̀-èdè | Nigerian |
Iṣẹ́ |
|
Ìgbà iṣẹ́ | 2003–present |
Olólùfẹ́ | Kolawole Ajeyemi[1][2] |
Ìbẹ̀rẹ̀ ìgbésí ayé àti ẹ̀kọ́ rẹ̀
àtúnṣeWọ́n bi ní ìlú Auchi, tí ó jẹẹ́ ìlú kan ní town in ìpínlẹ̀ Ẹdó ní orílẹ̀-èdẹ Nàìjírìà. Àmọ́ ṣá, ó bẹ̀rẹ̀ ayé rẹ̀ ní ìlú Ìbàdàn, tí ó jẹ́ olú ìlú ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ ní ìwọ̀ Oòrùn ilẹ̀ Nàìjíríà. Ó gba ìwé ẹ̀rí HND (Higher National Diploma) ní ilé-ẹ̀kọ́ gbogbo-nìṣe ìlú Ìbàdàn ìyẹn (Ibadan Polytechnic), lásìkọ́ yí, ó jẹ́ akẹgbẹ́ pẹ̀lú Dibie, C.B.N aka x7, Tóyìn Abraham ti fara hàn nínú ọ̀pọ̀lọpọ̀ eré, tí ó sì tún ṣẹ̀ṣẹ̀ kópa nínú sinimá àgbéléwò aré tí orúkọ̀ rẹ̀ ń jẹ́ Black Val.
Iṣẹ́ rẹ̀
àtúnṣeTóyìn bẹ̀rẹ̀ eré orí ìtàgé rẹ̀ nígbà tí gbajú-gbajà òṣèré orí-ìtàgé tí orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ Bukky Wright, wá sí ìlú Ìbàdàn láti yàwòrán eré kan .Ó ti darí, kópa àti gbé eré jáde fúnra rẹ̀, lára rẹ̀ ni Àlání Bàba Làbákẹ́ àti d Èmi ni. Wọ́n yàán gẹ́gẹ́ bí òṣèré amúgbá-lẹ́gbẹ̀ẹ́ obìnrin tó dára jùlọ (Best Supporting Actress) nínú eré orí ìtàgé tí orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ "Ẹ̀bi mi ni" nínú àmì ẹ̀yẹ 2013 Best of Nollywood Awards , bákan náà ni wọ́n yan Jọkẹ́ Múyìwá fún Best Lead Actress nínú eré tí àkọ́lé rẹ̀ ń jẹ́ Ayítakẹ̀. Ẹ̀wẹ̀, ọ̀pọ̀ àwọn olóṣèlú ló ti pèé láti bá wọn polongo ètò ìdìbò fún Ààrẹ ilẹ̀ Nàìjíríà tẹ́lẹ̀ tí ó jẹ́ adíje dupò sí orí àpèrè Ààrẹ ìyẹn Goodluck Ebele Jonathan ní ọdún 2015. Tóyìn pàá pàà só wípé òun lè kú torí ẹgbẹ́ òṣèlú People Democratic Party (PDP) kú[8] tí ó jẹ́ ẹgbẹ́ òṣèlú tí adíje dupò náà ti ń díje. Àmọ́ ṣá, ó padà yí gbólóhùn rẹ̀ padà wípé òun bẹ àwọn olólùfẹ́ òun wípé kí ẹnikẹ́ni ó má ṣe ta ẹ̀jẹ̀ ẹnikẹni sílẹ̀ lásìkò ìdìbò.
Àwọn eré ìtàgé rẹ̀
àtúnṣe- Okafor's Law (2016)
- Love is in the Hair (2016)
- Àlàní Bàbá Làbákẹ́ (2013)
- Ẹ̀bi mi ni (2013)
- Alákadá (2013)
- Ṣọlá fẹ́ pa mí
- Ghost and the tout (2018)
Àwọn fíìmù rẹ̀ tí a yàn
àtúnṣe- Alani Baba labake (2013)
- Ebimi ni (2013)
- Alakada (2009) bíi Yetunde
- Alakada 2 (2013) bíi Yetunde
- Okafor's Law (2016) bíi Tomi Tiiani
- What Makes you Tick (2016)
- Love is in the Hair (2016) bíi Constance
- Alakada Reloaded (2017) bíi Yetunde
- Esohe (2018) bíi Titilola
- Hakkunde (2017) bíi Yetunde
- Mentally (2017) bíi Ewa
- Tatu (2017) bíi Larayi
- London Fever (2017) bíi Food Seller
- Wives on Strike: The Revolution (2017) bíi Iya Bola
- Celebrity Marriage (2017) pẹ̀lú Tonto Dikeh, Felix Ugo Omokhodion, àti Jackie Appiah
- The Ghost and the Tout (2018) bíi Isla
- Seven and Half Dates (2018) bíi Abiodun
- Disguise (2018) bíi Gigi
- What just happened (2018)
- Elevator Baby (2019) bíi Abigail
- Don't Get Mad, Get Even (2019) bíi Ngozi
- "City Of Dreams" (2019) bíi Becky
- Made in Heaven (2019) bíi DPO
- Two Weeks in Lagos (2019) bíi Kemi
- The Millions (2019) bíi Adenike
- Kasanova (2019) bíi Bisola
- Bling Lagosians (2019) bíi Dunni Fernendez
- Nimbe (2019) bíi Uduak
- Diamonds In The Sky (2019) bíi Yesimi Gbeborun
- Fate of Alakada (2020) bíi Yetunde
- Dear Affy (2020) bíi Teni the Blogger
- Small Chops (2020) bíi Bar Manager
- Sola Fe Pami
- Kambili (2020) bíi Jessica
- Shadow Parties (2021) bíi Arike
- Aki and Pawpaw (2021) bíi Mama Nkiru
- The Prophetess (2021) bíi Prophetess Ajoke
- The Therapist (2021)[9] bíi Mrs. Priye
- Ghost and The Tout Too (2021) bíi Isla
- Day of Destiny (2021) bíi Captain
- King of Thieves (2022) bíi Bonuola
- The Stranger I Know (2022)[10] bíi Fasayo
- The Wildflower (2022)[11] bíi Mama Olisa
- Single Not Searching (2022) bíi Omowunmi
- Ijakumo: The Born Again Stripper (2022) bíi Asabi
- Imade (2023) bíi Màmá Imade
- Onyeegwu (2023) bíi Prophetess
- Malaika (2023)
- Arodan (2023) bíi Kukoyi
- Gangs of Lagos (2023) bíi Bamidele
Àtòjọ àwọn àmì-ẹ̀yẹ rẹ̀
àtúnṣeỌdún | Àmì-ẹ̀yẹ | Ìsọ̀rí | Iṣẹ́ | Èsì | Ìtọ́ka |
---|---|---|---|---|---|
2010 | Best of Nollywood Awards | Best Indigenous Actress in a Lead Role (Yoruba) | Awa Obinrin | Yàán | |
2011 | Best of Nollywood Awards | Best Indigenous Actress in a Lead Role (Yoruba) | Ikudoro | Yàán | |
2012 | Yoruba Movie Academy Awards | Best Actress in Leading Role | Yàán | ||
2013 | Yoruba Movie Academy Awards | Best Cross Over Actress | Jejeloye | Yàán | |
Best of Nollywood Awards | Best Actress in a Lead Role –Yoruba film | Alani Baba Labake | Yàán | ||
2016 | Best of Nollywood Awards | Best Actress in a Lead Role(Yoruba) | Metomi | Gbàá | |
2017 | Five Continents International Film Festival | Best Supporting Actress Feature Film | Hakkunde | Gbàá | [12] |
Best of Nollywood Awards | Best Supporting Actress –English | Tatu (film) | Wọ́n pèé | [13] | |
2018 | Africa Magic Viewers' Choice Awards | Best Supporting Actress | Tatu | Yàán | |
Africa Movie Academy Awards | Best Actress in a Supporting Role | Esohe | Yàán | ||
2020 | Africa Magic Viewers' Choice Awards | Best Actress in a Drama | Elevator Baby | Gbàá | [14] |
Best Actress in a Comedy | Bling Lagosians | Wọ́n pèé | |||
Best Actress in a Comedy | Kasanova | Wọ́n pèé | |||
Best of Nollywood Awards | Best Actress in a Lead role –English | Elevator Baby | Wọ́n pèé | [15] | |
NET Honours | Most Popular Actress | Yàán | |||
2023 | Legit.ng's Readers Choice Awards | Best Actress | Yàán | ||
NET Honours | Most Popular Actress | Yàán | |||
2024 | Legit.ng Entertainment Awards | Best Actress | Yàán |
Ẹ tún le wo
àtúnṣe- List of Nigerian film producers
Àwọn ìtọ́ka sí
àtúnṣe- ↑ "Fans claim Toyin Abraham is expecting another child - NewsWireNGR". NewsWireNGR. May 3, 2022. Retrieved May 29, 2022.
- ↑ Adebayo, Segun (January 23, 2022). "My husband not living off my money, he works hard —Toyin Abraham". Tribune Online. Retrieved May 29, 2022.
- ↑ "Nollywood Star, Aimakhu Now To Be Called Toyin Abraham". Channels Television. https://www.channelstv.com/2016/12/29/nollywood-star-aimakhu-now-to-be-called-toyin-abraham/. Retrieved 30 December 2016.
- ↑ Mix, Pulse (May 27, 2022). "Purit unveils Toyin Abraham as brand ambassador for 30 years anniversary". Pulse Nigeria. Retrieved May 29, 2022.
- ↑ Obinna, Chioma (April 15, 2022). "Toyin Abraham soars higher!". Vanguard News. Retrieved May 29, 2022.
- ↑ Bada, Gbenga (May 27, 2022). "Toyin Abraham, Odunlade rejoice as Bamidele Onalaja celebrates with widows - The Nation Newspaper". The Nation Newspaper. Retrieved May 29, 2022.
- ↑ "Toyin Abraham and Lizzy Anjorin: Wetin cause dia gbas-gbas - BBC News Pidgin". BBC News Pidgin. May 26, 2021. Retrieved May 29, 2022.
- ↑ "I am ready to die for PDP-Toyin Aimakhu". Gistmaster. Archived from the original on 2018-07-26. https://web.archive.org/web/20180726071955/http://niyitabiti.net/2015/03/i-am-ready-to-die-for-pdp-toyin-aimakhu/. Retrieved 2018-01-03.
- ↑ "Toyin Abraham, Rita Dominic return to set for The Therapist". The Nation. 2 September 2020. Retrieved 6 April 2021.
- ↑ Augoye, Jayne (2022-07-26). "Toyin Abraham, Bimbo Akintola, Akin Lewis star in new romantic-comedy 'The Stranger I Know'". Premium Times Nigeria (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2022-08-23.
- ↑ "Damilare Kuku, Toyin Abraham, Sandra Okunzuwa Star in – THISDAYLIVE". www.thisdaylive.com. Retrieved 2022-08-23.
- ↑ "Toyin Abraham". IMDb. Retrieved 10 October 2020.
- ↑ Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid
<ref>
tag; no text was provided for refs namedauto
- ↑ "AMVCA 2020: Full list of winners". Pulse Nigeria. 14 March 2020. Retrieved 10 October 2020.
- ↑ Augoye, Jayne (2 December 2020). "2020 BON: Here are 5 nominees for 'Best Kiss' category". Premiumtimesng.com (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 11 October 2021.
Àwọn ìjásóde
àtúnṣe- Toyin Abraham on IMDb