Wikipedia:Àìṣojúṣájú

Yes check.svg Ojúewé yìí ní ìpinu ọ̀nà ìṣiṣẹ́ kan Wikipedia nínú. Ó jẹ́ èso ìfohùnṣọ̀kan, bẹ́ ẹ̀ sì ni ó jẹ́ gbígbàgbọ́ pé gbogbo àwọn oníṣe gbọ́dọ̀ tẹ̀lé wọn gbámúgbámú. Ẹ le ṣàtúnṣe àkóónú ojúewé náà sùgbọ́n ẹ jọ̀wọ́ ọ mọ́ ṣe ìyípadà ìpinu ọ̀nà ìṣiṣẹ́ kankan láì kọ́kọ́ filọ àwọn oníṣe yìókù.

Àìṣojúṣájú