Wikipedia:Àwọn Ìṣẹ̀lẹ̀ Bíi Ọjọ́ Òní/Ọjọ́ 13 Oṣù Kẹfà
- 1934 – Adolf Hitler àti Benito Mussolini pàdé ní Venice, Itálíà
- 1967 – Ààrẹ Orílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà Lyndon B. Johnson yan Thurgood Marshall láti di adájọ́ aláwọ̀dúdú àkọ́kọ́ ní Ilé-ẹjọ́ Gígajùlọ Orílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà.
Àwọn ọlọ́jọ́ìbí lóòní...
- 1928 – John Forbes Nash, Jr., onímọ̀ matimátíìkì ará Amẹ́ríkà (al. 2015)
- 1944 – Ban Ki-moon, Akọ̀wé-Àgbà Àjọ àwọn Orílẹ̀-èdè ará Kòréà Gúúsù
- 1954 – Ngozi Okonjo-Iweala, onímọ̀ òkòwò àti olóṣèlú ará Nàìjíríà
Àwọn aláìsí lóòní...
- 1972 – Georg von Békésy, onímọ̀ físíksì ará Húngárì (ib. 1899)
- 1948 – Osamu Dazai (fọ́tò), olùkọ̀wé ará Jèpánù (ib. 1909)
- 1980 – Walter Rodney, akọìtàn ará Guyana àti olóṣèlú (ib. 1942)