Wikipedia:Àwọn Ìṣẹ̀lẹ̀ Bíi Ọjọ́ Òní/Ọjọ́ 14 Oṣù Kẹfà
- 1822 – Charles Babbage dá àbá ẹ̀rọ ìyàtò nínú ìwé tó kọ sí Ẹgbẹ́ Atòràwọ̀ Ọba pẹ̀lú àkọlé "Àjákọ lórí ìmúlò ẹ̀rọ sí ìṣíròpapọ̀ àwọn tábìlì atòràwọ̀ àti onímatimátìkì".
- 1900 – Hawaii di agbègbè àwọn Ìpínlẹ̀ Aṣọ̀kan Amẹ̀ríkà.
Àwọn ọlọ́jọ́ìbí lóòní...
- 1736 - Charles-Augustin de Coulomb, asefisiksi ara Fransi (al. 1806)
- 1899 – Yasunari Kawabata, olukowe ara Japan, elebun Nobel (al. 1972)
- 1928 - Che Guevara (foto), olujidide ara Argentina (al. 1967)
Àwọn aláìsí lóòní...
- 1920 – Max Weber, aseoroawujo ara Jemani (ib. 1864)
- 1986 – Jorge Luis Borges, olukowe ara Argentina (ib. 1899)
- 2007 – Kurt Waldheim, oloselu ati agbailu ara Austria (ib. 1918)