Wikipedia:Àwọn Ìṣẹ̀lẹ̀ Bíi Ọjọ́ Òní/Ọjọ́ 20 Oṣù Kẹ̀sán
- 1946 – Ayẹyẹ fíìmù ti Cannes àkọ́kọ́ ti waye, tí àti dá dúró fún ọdún méje nítorí ogún àgbáyé kejì.
- 1962 – Ọmọ Afíríkà Amẹrika kan tí a pè ní James Meredith, tí ní ìdíwọ́ díẹ̀ láti wọ ilé-ìwé Fásitì ti Mississippi.
Àwọn ọlọ́jọ́ìbí lóòní...
- 1925 – Bobby Nunn, akọrin Amẹ́ríkà tí R&B (d. 1986)
- 1934 – Sophia Loren, Òṣeré tí orílẹ̀ èdè Italy
Àwọn aláìsí lóòní...
- 1994 – Abioseh Nicol, olóògùn , ọmọ̀wé, àti aṣojú ìjọba tí orílẹ̀ èdè Sierra Leone (b. 1924)
- 1996 – Reuben Kamanga, olóṣèlú orílẹ̀-èdè Zambia, igbá-kejì Ààrẹ alàkọ́kọ́ tí Zambia (b. 1929)