Wikipedia:Àwọn Ìṣẹ̀lẹ̀ Bíi Ọjọ́ Òní/Ọjọ́ 22 Oṣù Kẹ̀sán
Ọjọ́ 22 Oṣù Kẹ̀sán: Ọjọ́ Ìlómìnira ní Bùlgáríà (1908) àti Málì (1960)
- 1862 – Ààrẹ ilẹ̀ àwọn Ìpínlẹ̀ Aṣọ̀kan Amẹ́ríkà Abraham Lincoln pàṣẹ Ìpolongo Ìtúnisílẹ̀, tó fi òmìnira fún gbogbo àwọn ẹrú tó wà ní agbègbè Àjọparapọ̀ láti Oṣù Kínní, 1863.
- 1957 – François "Papa Doc" Duvalier jẹ́ dídìbòyàn sí ipò bíi Ààrẹ ilẹ̀ Hàítì.
Àwọn ọlọ́jọ́ìbí lóòní...
- 1791 – Michael Faraday, aṣesáyẹ́nsì ará Ilẹ̀gẹ̀ẹ́sì (al. 1867)
- 1902 – Ruhollah Khomeini, olòrí ìjídìde ará Ìránì (al. 1989)
- 1946 – King Sunny Adé (àwòrán), olórin ará Nàìjíríà
Àwọn aláìsí lóòní...
- 1828 – Shaka, ọba àwọn Súlú ará Gúúsù Áfríkà (ib. 1787)
- 1956 – Frederick Soddy, aṣiṣẹ́ògùn ará Ilẹ̀gẹ̀ẹ́sì (ib. 1877)
- 1969 – Adolfo López Mateos, Ààrẹ ilẹ̀ Mẹ́ksíkò (b. 1909)