Wikipedia:Àwọn Ìṣẹ̀lẹ̀ Bíi Ọjọ́ Òní/Ọjọ́ 25 Oṣù Kínní
- 1575 – Luanda, olúìlú Angola jẹ́ dídásílẹ̀ látọwọ́ olùtọ́ṣọ́nà ará Potogí Paulo Dias de Novais.
- 1924 – Àwọn Ìdíje Òlímpíkì Ìgbà Otútù àkọ́kọ́ bẹ̀rẹ̀ ní ẹsẹ̀ Mont Blanc ní Chamonix, Haute-Savoie, France, pẹ̀lú àwọn eléré orí pápá bíi 200 láti àwọn orílẹ̀-èdè 16.
- 1971 – Idi Amin Dada fipágbàjọba ológun lọ́wọ́ Ààrẹ Milton Obote, láti bẹ̀rẹ̀ ìjọba ológun ọdún mẹ́jọ ní Ùgándà.
Àwọn ọlọ́jọ́ìbí lóòní...
- 1627 – Robert Boyle, onímọ̀ kẹ́místrì ará Írẹ́lándì (al. 1691)
- 1736 – Joseph Louis Lagrange, onímọ̀ mathimátíkì ọmọ Itálíà (al. 1813)
- 1938 – Etta James (fọ́tò), akọrin ará Amẹ́ríkà (al. 2012)
- 1942 – Eusébio, agbábọ́ọ̀lù-ẹlẹ́sẹ̀ Pọ́rtúgàl
Àwọn aláìsí lóòní...
- 1947 – Al Capone, olórí agbájọ ìwà ọ̀daràn ará Amẹ́ríkà (ib. 1899)
- 1994 – Stephen Cole Kleene, onímọ̀ mathimátíkì ará Amẹ́ríkà (ib. 1909)
- 2005 – Manuel Lopes, olùkọ̀wé ará Cape Verde (ib. 1907)