Wikipedia:Àwọn Ìṣẹ̀lẹ̀ Bíi Ọjọ́ Òní/Ọjọ́ 26 Oṣù Kàrún
Ọjọ́ 26 Oṣù Kàrún: Ọjọ́ Ìlómìnira ní Georgia(1918) àti Guyana (1966)
- 1983 – Ìmínlẹ̀ kíkan ìtóbi iye 7.7 ṣẹlẹ̀ ní Japan, èyí fa tsunami, tó fa ikú pa ènìyàn 104 àti tó pa ẹgbẹẹ̀gbẹ̀rún ènìyàn lára.
- 2008 – Àgbàrá ṣẹlẹ̀ ní apáìlàòrùn àti apágúsù Ṣáínà tó fa ikú ènìyàn 148 tó sì jẹ́ kí àwọn ènìyàn 1.3 ó kúrò nílé wọn.
Àwọn ọlọ́jọ́ìbí lóòní...
- 1926 – Miles Davis, afọnfèrè, olórí ẹgbẹ́-alùlù àti akórinjọ ará Amẹ́ríkà (al. 1991)
- 1929 – J.F. Ade Ajayi, akọìtàn ará Nàìjíríà (al. 2014)
- 1949 – Pam Grier (foto), òṣeré ará Amẹ́ríkà
Àwọn aláìsí lóòní...
- 1976 – Martin Heidegger, amòye ará Jẹ́mánì (ib. 1889)
- 2002 – Mamo Wolde, asáré ará Ethiópíà (ib. 1932)
Ṣíṣàtúnṣe ojúewé yìí látọwọ́ àwọn oníṣe tuntun tàbí àwọn oníṣe aláìtíìforúkọsílẹ̀ jẹ́ tí tìpa lọ́wọ́lọ́wọ́. See the protection policy and protection log for more details. If you cannot edit this ojúewé and you wish to make a change, you can submit an edit request, discuss changes on the talk page, request unprotection, log in, or create an account. |