Wikipedia:Àwọn Ìṣẹ̀lẹ̀ Bíi Ọjọ́ Òní/Ọjọ́ 3 Oṣù Kejìlá
- 1818 – Illinois di ìpínlẹ̀ Orílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà 21k.
- 1976 - Fidel Castro di Ààrẹ ilẹ̀ Kúbà.
- 1976 – Ìgbìdánwò láti pa Bob Marley wáyé.
Àwọn ọlọ́jọ́ìbí lóòní...
- 1857 – Joseph Conrad, Olùkọ̀wé ọmọ Pólàndì ará Brítánì (al. 1924)
- 1884 – Rajendra Prasad, Ààrẹ àkọ́kọ́ ilẹ̀ India (al. 1963)
- 1925 – Kim Dae-jung, Ààrẹ ilẹ̀ Kòréà Gúúsù (al. 2009)
Àwọn aláìsí lóòní...
- 2000 – Gwendolyn Brooks (fọ́tò), akọewì ará Amẹ́ríkà (ib. 1917)
- 2004 - Shiing-Shen Chern, onimathimatiki ara Saina