Wikipedia:Àwọn Ìṣẹ̀lẹ̀ Bíi Ọjọ́ Òní/Ọjọ́ 4 Oṣù Kẹrin
Ọjọ́ 4 Oṣù Kẹrin: Ọjọ́ òmìnira ní Senegal (1960)
- 1850 – Idasile ilu Los Angeles, California.
- 1968 – James Earl Ray yìnbọn pa Dr. Martin Luther King, Jr. ní ilé-ìtura kan ní Memphis, Tennessee.
- 2002 – Ìjọba ilẹ̀ Angola àti àwọn ọlọ́tẹ̀-ogun UNITA fọwọ́bọ̀wé àdéhùn àlááfìà tó fòpin sí Ogun Abẹ́lé ilẹ̀ Àngólà.
Àwọn ọlọ́jọ́ìbí lóòní...
- 1913 – Muddy Waters, olórin ará Amẹ́ríkà (al. 1983)
- 1928 – Maya Angelou (foto), olukowe ara Amerika (al. 2014)
- 1951 – Hun Sen, alakoso agba ile Kambodia
- 1972 – Jill Scott, akorin ara Amerika
Àwọn aláìsí lóòní...
- 1968 – Martin Luther King, Jr., alakitiyan ara Amerika (ib. 1929)
- 1972 – Adam Clayton Powell Jr., oloselu ara Amerika (ib. 1908)
- 1979 – Zulfikar Ali Bhutto, aare ati alakoso agba ile Pakistan (ib. 1928)