Wikipedia:Ìtọrọ láti di alámòjútó/Macdanpets

Àkékúrús:
WP:RFA
WP:RFX
WP:Àpẹrẹ

Àwọn ìfi orúkosílẹ̀ fún alámòjútó tó ń lọ lọ́wọ́lọ́wọ

àtúnṣe

Àkókò tí a wà lọ́wọ́lọ́wọ́ ni

Ọjọ́ Àìkú 29 Oṣù Kejìlá 2024


Ijíròrò tó tẹ̀le yìí jẹ́ àkójọ ìjíròrò pẹ̀lú ìbéèrè fún ìparẹ́ àpilẹ̀kọ tó wà lókè. Ẹ jọwọ, ẹ má ṣe ṣe àtúnṣe sí i. Ẹ máa fi àwọn èrò tuntun yín sí ojú ìjíròrò tó yẹ (bíi ojú-ewe ìjíròrò àpilẹ̀kọ tàbí nígbà àyẹ̀wò ìparẹ́). Ẹ má ṣe fi àtúnṣe kankan sí ojú ewe yìí mọ́.

'  Ó yege'. T CellsTalk 12:43, 18 Oṣù Ọ̀wàrà 2024 (UTC)[ìdáhùn]


Ọ̀rọ̀ ìforúkọsílẹ̀

àtúnṣe

Mo kí i yín o gbogbo ẹ̀yin akẹgbẹ́ mi àtàtà, orúkọ oníṣẹ́ mi ni Macdanpets, mò ń béèrè fún àtìlẹ́yìn yín láti jẹ́ alábòójútó pẹ́pẹ́ Wikipedia Yorùbá. Mo ti jẹ́ ọ̀kan lára àwọn aláfikún ìmọ̀ Wikipedia Yorùbá láti ọdún 2018, mo sì ti kọ ẹgbẹlẹmùkú àyọkà lóníraǹran. Ọ̀pọ̀lọpọ̀ àyọkà ni mo ti ṣe àtúnṣe sí pẹ̀lú. Lájorí rẹ̀ ni pé mo wà lára àwọn igbimọ̀ Yoruba wikimedians User Group. Mò ń fẹ́ ìyọ̀ǹda yìí láti lè fún mi ní àǹfàní láti ma mójú tó àwọn àyọkà tí a ba n kọ lórí pẹpẹ Wikipedia Yorùbá. Inú mi a dùn bí ẹ bá tìmí lẹ́yìn láti ṣe èyí. Macdanpets 14:49, 9 Oṣù Ọ̀wàrà 2024 (UTC)

Ìjíròrò

àtúnṣe

Jọ̀wọ́ sọ̀rọ̀ tútù tó dára, pẹ̀lụ́ ìrẹ̀lẹ̀. Tí o kò bá mọ oníṣẹ́ tí ó fẹ́ di alábójútó yìí dáradára, Jọ̀wọ́ ṣe àyẹ̀wo àfikún rẹ̀ dáradára kí o tó dási.

Faramọ́ (support)
àtúnṣe
  1. Mo faramọ́ kí ọ̀gbẹ́ni Dansu Peter tí orúkọ oníṣẹ́ wọn jẹ́ Macdanpets di alámòójútó lórí ìkànnì Yorùbá Wikipedia yìí.Dokimazo99 (ọ̀rọ̀) 04:50, 12 Oṣù Ọ̀wàrà 2024 (UTC)[ìdáhùn]
  2. Mo faramọ́ kí ọ̀gbẹ́ni Dansu Peter tí orúkọ oníṣẹ́ wọn jẹ́ Macdanpets di alámòójútó lórí ìkànnì Yorùbá Wikipedia yìí.Olaide07.
  3. Mo faramọ́ kí ọ̀gbẹ́ni Dansu Peter tí orúkọ oníṣẹ́ wọn jẹ́ Macdanpets di alámòójútó lórí ìkànnì Yorùbá Wikipedia yìí.Billy bindun (ọ̀rọ̀) 04:50, 12 Oṣù Ọ̀wàrà 2024 (UTC)[ìdáhùn]
  4. Mo faramọ́ kí Ọ̀gbẹ́ni Dansu Peter tí orúkọ oníṣẹ́ wọn jẹ́ Macdanpets di alámòójútó lórí ìkànnì Yorùbá Wikipedia yìí. Oluwatoyin Ayomide (ọ̀rọ̀)
  5. Mo faramọ́ kí ọ̀gbẹ́ni Dansu Peter tí orúkọ oníṣẹ́ ẹ wọ́n jẹ́ Makdanpets di alámòójútó lórí ìkànnì Wikipedia látàrí àwọn iṣẹ́ takuntakun tí wọ́n ti ṣe Apalopadidun1 (ọ̀rọ̀)
  6. Èmi faramọ́ ọ̀gbẹ́ni Dansu Peter tí orúkọ oníṣẹ́ rẹ̀ jẹ́ Macdanpets láti jẹ́ alámòjútó ìkànnì Yoruba Wikipedia yìí látara iṣẹ́ ribiribi tí ó ti ṣe. Ruth-4life (ọ̀rọ̀) 04:30, 13 Oṣù Ọ̀wàrà 2024 (UTC)[ìdáhùn]
  7. Mo faramọ kí Macdanpets ó di alámòójútó tuntun fún WikipediaAgbalagba (ọ̀rọ̀) 07:47, 13 Oṣù Ọ̀wàrà 2024 (UTC)[ìdáhùn]
lòdìsí (oppose)
àtúnṣe
Ìdásí gbogboògbò (general comment)
àtúnṣe

Pa cache ojú ewé rẹ́ tí àwọn ìforúkosílẹ̀ kó bá dé ojú ìwọ̀n.

Ijíròrò lókè yìí ni a fipamọ sílẹ̀ gẹ́gẹ́ bi àkójọ àwọn òfin àròkò náà. Ẹ jọwọ, ẹ má ṣe ṣe àtúnṣe sí i. Ẹ máa fi àwọn èrò tuntun yín sí ojú ìjíròrò tó yẹ (bíi ojú-ewe ìjíròrò àpilẹ̀kọ tàbí nígbà àyẹ̀wò ìparẹ́). Ẹ má ṣe fi àtúnṣe kankan sí ojú ewe yìí mọ́. Ẹ má ṣe fi àtúnṣe kankan sí ojú ewe yìí mọ́.