Wikipedia:Ìtọrọ láti di alámòjútó/Wikicology 2

Àkékúrús:
WP:RFA
WP:RFX
WP:Àpẹrẹ

Àwọn ìfi orúkosílẹ̀ fún alámòjútó tó ń lọ lọ́wọ́lọ́wọ àtúnṣe

Àkókò tí a wà lọ́wọ́lọ́wọ́ ni

Ọjọ́ẹtì 29 Oṣù Kẹta 2024


Ọ̀rọ̀ ìforúkọsílẹ̀ àtúnṣe

Mo kí yin o gbogboògbò,

Mo fẹ́ kí ẹ fún mi ní irinṣẹ́ tí maa fi dojú ìjà kọ àwọn aṣèbàjẹ́ ní ibí àti láti pa ojú ewé tí ó yẹ kí o di píparẹ́ kíákíá rẹ. Èdè yìí jẹ́ èdè abínibí mi tí mo sì jẹ́ ẹnìkejì tí ó ń ṣisẹ́ takuntakun níbí tí mo sì ti ṣe àtúnṣe tí ó ju 3000+ lọ pẹ̀lú wípé mo tún ti kọ ayọkà tí ó ju 200 lọ. Inú mi á dùn tí ẹ bá lè fún mi láàyè láti ṣe iṣẹ́ takuntakun nibí. Mo fi oruko Sile no ni odun kan seyin, sugbon mi ko tesiwaju. E wo Wikipedia:Ìtọrọ láti di alámòjútó/Wikicology

(English translation)Dear all,

I'd like to request the admin tools to fight vandalism and to delete pages that meet the criteria for speedy deletion. I am a native speaker of Yoruba Language and the second most active editor on this Wiki with 3000+ edits and 200+ articles created. I'll be glad if am given the job and I won't abuse the admin privileges. I nominated myself for adminship over a year ago but I withdrew my nomination for personal reason. See Wikipedia:Ìtọrọ láti di alámòjútó/Wikicology. Thank you. Wikicology (ọ̀rọ̀) 09:01, 6 Oṣù Kínní 2018 (UTC)[ìdáhùn]

Àkékúrús:
WP:RFA
WP:RFX
WP:Àpẹrẹ

Àwọn ìfi orúkosílẹ̀ fún alámòjútó tó ń lọ lọ́wọ́lọ́wọ àtúnṣe

Àkókò tí a wà lọ́wọ́lọ́wọ́ ni

Ọjọ́ẹtì 29 Oṣù Kẹta 2024


Àkókò ìbò àtúnṣe

Ètò ìdìbò yí bẹ̀ẹ̀rẹ̀ ní 10:01:59 06/01/2018 tí ó sì ma parí ní 10:01:59 13/01/2018.

(English translation) Voting is open from 6th of January, 18:10:01 to 13th of January 18: 10:01

Ìjíròrò àtúnṣe


Faramọ́ (support) àtúnṣe
lòdìsí (oppose) àtúnṣe
Ìdásí gbogboògbò (general comment) àtúnṣe