Wikipedia:Account creator
Àdàkọ:Information page Àdàkọ:Nutshell
Olùdá àkọpamọ́ orúkọ oníṣẹ́ fún àwùjọ àwọn oníṣẹ́ Wikipẹ́día (accountcreator user group) ni ó tún ní ẹ̀tọ́ sí irinṣẹ́ yí láti dá àkọpamọ́ àwọn oníṣẹ́ tuntun tí wọ́n bá nífẹ̀ẹ́ sí dídá orúkọ oníṣẹ́.
Àwọn ohun tí olùdá àkọpamọ́ orúkọ oníṣẹ́ lè ṣe
àtúnṣeÀwọn àkọpamọ́ tí a dá lábẹ́ user group nípasẹ̀ olùdá àkọpamọ́ orúkọ oníṣẹ́ yóò lè lo àwọn irinṣẹ́ tí ó wà lábẹ́ ìdá àkọpamọ́ orúkọ oníṣẹ́ láti ṣe:
- Ní ànfàní láti dá àkọpamọ́ orúkọ oníṣẹ́ tí ó ju mẹ́fà lọ[1] láàrin wákàtí ẹ́rìnlélógún ó ní ànfàní láti lo irinṣẹ́ pàtàkì yí láti fi Special:dá àkọpamọ́ orúkọ oníṣẹ́ tàbí kí ó lo irinṣẹ́ mìíràn bi (the noratelimit flag).
- Ó Ní ànfàní láti ṣe "àyídá-yidà" kí ó sì dá orúkọ oníṣẹ́ kan tí fara jọ orúkọ oníṣẹ́ tí ó ti wà tẹ́lẹ̀ nípa lílo ìṣẹ́dá orúkọ oníṣẹ́ afara-jọra (the override-antispoof flag).
- Ó ní ànfàní láti ṣàyípadà kí ó sì dá orúkọ oníṣẹ́ tí wọ́n ti pagidí tí ó sì ti wọ "ìwé ẹ̀kọ̀" (blacklist) nípa lílo àká ìwé ẹ̀kọ̀ (the tboverride-account flag).
- ↑ àdínkù lè bá ànfàní yí bí olùdá àkọpamọ́ náà bá ń ṣi agbára rẹ̀ lò.
Láti di olùdá àkọpamọ́ oníṣẹ́
àtúnṣeLáti ní àṣẹ àsíá ìjẹ́ olùdá àkọpamọ́ orúkọ oníṣẹ́, o gbúdọ̀ jẹ́ ẹni tí ṣiṣẹ́ déédé tó sì ní ìrírí tó gbòòrò wo ìlànà àti ìtọ́ni (ACC), tí wọn yóò sì ṣàfihan rẹ̀ lórí pátákó ajúwe Wikimedia Foundation. Oníṣẹ́ tí ó bá fìfẹ́ hàn sí àsíá àṣẹ yí ti gbúdọ̀ gbìyànjú láti dá àkọpa.ọ́ orúkọ oníṣẹ́ tí ó ti tó mẹ́fà ṣáájú kí ó bèrè fún ìyọnda àṣẹ ìlò irinṣẹ́ ìdá àkọpamó orúkọ oníṣẹ́ pẹ̀lú ìtàkùn yí Wikipedia:Requests for permissions/Olùdá àkọpamọ́ orúkọ oníṣẹ́.
Àwọn kókó pàtàkì mìíràn
àtúnṣeÀṣẹ àsíá ìdá àkọpamọ́ orúkọ oníṣẹ́ ni a ma ń fún àwọn oníṣẹ́ Wikipẹ́día tó bá peregedé tí wọ́n sì ń ṣiṣẹ́ olóòrè-kóòrè lórí pẹ́lú nìkan ni wọ́n ní ànfàní láti lo àwọn irinṣẹ́ pàtàkì tí ó wà lábẹ́ àṣẹ ìdá àkọpamọ́ orúkọ oníṣẹ́ ní ìlànà tiwọn. Ẹ̀wẹ̀, Yorùbá Wikipẹ́día ti ní àwọn àtòjọ àwọn oníṣẹ́ 1 wọ̀nyí tí wọn ti gba àṣẹ tí wọ́n sì gbé àsíá ìdá àkọpamọ́ orúkọ oníṣẹ́ lábẹ́ orúkọ wọn gbogbo.
Ẹ tún lè wo
àtúnṣe- Àtòjọ àwọn oníṣẹ́ tí wọ́n ti ní àṣẹ ìdá àkọpamọ́ orúkọ oníṣẹ́ ní abẹ́ accountcreator Yorùbá Wikimedians UG
- {{Accountcreator topicon}}—a àwọn tó ga jùlọ èyí ń fi iye àwọn olùdá àkọpamọ́ orúkọ oníṣẹ́ bí ipò wọn ṣe ga sí hàn.
- {{User wikipedia/Accountcreator}}—a àpótí irinṣẹ́ èyí ń ṣàfihàn ẹ́tọ́ àti agbára tí wọ́n ní hàn lábẹ́ orúkọ wọn.
- {{User wikipedia/acclabsuser}}—a àpótí irinṣẹ́ èyí wà fún ṣíṣàfihàn àṣẹ àti ẹ̀tọ́ tí oníṣẹ́ tí ó ní àsíá àṣẹ yí ní sí ilé agbára
- Ìdá orúkọ oníṣẹ́ fún ọ̀gọ̀rọ̀ ènìyàn