Wizard Chan

Olórin ilẹ̀ Nàìjíríà

Fuayefika Maxwell ( tí wọ́n bí ní 26, June) tí ọ̀pọ̀ èèyàn mọ̀ sí ‘Wizard Chan’ jẹ́ olórin Afro ti orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.[1] Ó ṣe àgbéjáde orin rẹ̀ àkọ́kọ́ tí àkọ́lé rẹ̀ jẹ́ 'Halo Halo' ní ọdún 2020. Àmọ́, ìgbà tí ó ṣẹ̀ ṣe àgbéjáde orin tí àkọ́lé rẹ̀ jẹ́ ‘Earth Song’ ni ó di gbajúmọ̀, ìyẹn ní oṣù December ọdún 2022. Ní ọdún 2023, ó gba àmì-ẹ̀yẹ The Headies àti Galaxy Music Awards.[2]

Wizard Chan
Orúkọ àbísọFuayefika Maxwell
Ọjọ́ìbíÀsìṣe ìgbéọ̀rọ̀sílẹ̀: Àìdámọ̀ ọ̀rọ̀ "dd". YYYY (YYYY-MM-DD) (ọmọ ọdún Àsìṣe ìgbéọ̀rọ̀sílẹ̀: Àìdámọ̀ ọ̀rọ̀ "yyyy".)
Port Harcourt, Rivers State, Nigeria
Irú orin
Occupation(s)
  • Singer
  • songwriter
Instruments
  • Vocals
  • piano
Years active2020–present
LabelsChan Empire

Ìbẹ̀rẹ̀pẹ̀pẹ̀ ayé rẹ̀

àtúnṣe

Wọ́n bí Maxwell ní 26 June ní ìlú Okrika, ní Ìpínlẹ̀ Rivers, sínú ìdílé Olóyè & Mrs Fuayefika, gẹ́gẹ́ bíi àbígbẹ̀yìn nínú àwọn ọmọ márùn-ún. Ó jẹ́ ọmọ ìbílẹ̀ Port Harcourt, bẹ́ẹ̀ sì ni ó lo ìgbà èwe rẹ̀ níbẹ̀. Ó gba ẹ̀kọ́ girama láti De World International Secondary School, ní Ìpínlẹ̀ Rivers. Ó kẹ́kọ̀ọ́ gboyè ní Wisconsin International University College ní Accra, Ghana níbi tí ó ti kẹ́kọ̀ọ́ nípa ìpolówó ọjà. Ó padà sí orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, tí ó sì lọ sí Ìpínlẹ̀ Sokoto fún NYSC.[3]

Àtọ̀jọ àwọn orin rẹ̀

àtúnṣe

Àwọn orin àdákọ

àtúnṣe
  • Halo Halo
  • Truth
  • Y.O.L.O
  • Miss You -- Thousand Voice ft Wizard Chan (2022)
  • Earth Song
  • Highlife
  • Moses ft Boma Nime [4]
  • Drumline -- 01FRNCH ft Wizard Chan
  • Beast of Our nation -- King Perryy ft Wizard Chan & Tuzi [5]

Àwọn àmì-ẹ̀yẹ

àtúnṣe
Ọdún Àmì-ẹ̀yẹ Ìsọ̀rí Ẹni tí wọ́n yán Èsì Ìtọ́ka
2023 The Headies Best Alternative Song of the year Earth song Gbàá [6]
Best Songwriter of the Year Himself Wọ́n pèé [6]
Galaxy Music Awards Best Alternative Song of the year Earth song Gbàá [7][8]

Àwọn ìtọ́kasí

àtúnṣe