Wọlé Òjó ni wọ́n bí ní ọjọ́ Kẹfà oṣù Kẹfà, ọdún 19884.(bí 6 Okudu 1984). Ójẹ́ òṣèré jẹ oṣere orí ìtàgé ọmọ ilẹ̀ Nàìjíríà. Ó dìlú mọ̀ọ́ká ní inú iṣẹ́ sinimá nílẹ̀ Nàìjíríà ní ọdún 2009, lẹ́yìn tí ó gbé ipò kẹ́rin nínú ìdíje Amstel Malta Box Office.
Wole Ojo |
---|
Ọjọ́ìbí | (1984-06-06)6 Oṣù Kẹfà 1984 |
---|
Orílẹ̀-èdè | Nigerian |
---|
Iṣẹ́ | Actor |
---|
Notable work | The Child |
---|
Ó gba oyè ìmọ̀ ẹ̀kọ́ nínú iṣẹ́ Àtinúdá (Creative Arts) láti ilé-ẹ̀kọ́ Fásitì ìlú Èkó.
Àwọn eré-àgbéléwò rẹ̀ gbogbo
àtúnṣe
Ọdún |
Fíìmù |
Ojúṣe |
Ọ̀rọ̀
|
2011 |
Maami |
Kashimawo |
Eré-oníṣe
|
2012 |
When Fishes Drown |
Tony |
Eré-oníṣe
|
2013 |
Conversations at Dinner |
Chidi Obi |
Eré-oníṣe
|
2014 |
Umbara Point |
Jelani |
Thriller
|
Perfect Union |
Steve Kadiri |
Eré-oníṣe
|
Brave |
Nathan Doga |
Fíìmù kékeré
|
2015 |
The MatchMaker |
Bryan |
fíìmù ajẹmọ́-ìfẹ́
|
Out of Luck |
Seun |
Eré-oníṣe
|
7 Inch Curve |
Kamani |
Eré-oníṣe
|
2016 |
Beyond Blood[1] |
|
fíìmù ajẹmọ́-ìfẹ́
|
Entreat[2] |
Segun Adeoye |
fíìmù ajẹmọ́-ìfẹ́
|
2018 |
Bachelor's Eve[3] |
Uche |
Eré-oníṣe
|
Àwọn àmì-ìdánilọ́lá tí ó gbà
àtúnṣe
Ọdún
|
Àmì-ẹ̀yẹ
|
Ìsọ̀rí
|
Olùgbà
|
Èsì
|
2010
|
6th Africa Movie Academy Awards[4]
|
Most Promising Actor
|
The Child
|
Wọ́n pèé
|
2014
|
City People Entertainment Awards[5]
|
Best New Actor (Yoruba)
|
|
Wọ́n pèé
|
2013
|
2013 Nollywood Movies Awards[6]
|
Best Actor (Indigenous)
|
Maami
|
Wọ́n pèé
|
2015
|
2015 Africa Magic Viewers Choice Awards[7]
|
Best Actor in a Drama
|
Brave
|
Wọ́n pèé
|
2015 Nigeria Entertainment Awards[8]
|
Actor of the Year (Nollywood)
|
Brave
|
Wọ́n pèé
|
- ↑ Helen, Ajomole (17 February 2016). "Popular actor shares challenges faced as an entertainer". naij.com. Archived from the original on 31 July 2017. Retrieved 30 July 2017.
- ↑ Izuzu, Chidumga. ""Entreat": Watch Dakore Akande, Alexx Ekubo, Sadiq Daba, Wole Ojo in star studded trailer". pulse.ng. Archived from the original on 31 July 2017. Retrieved 30 July 2017.
- ↑ Jayne Augoye (January 3, 2018). "Wole Ojo, Kehinde Balogun, Gbenro Ajibade star in new film, "Bachelor’s Eve"". Premium Times. https://www.premiumtimesng.com/entertainment/nollywood/254320-wole-ojo-kehinde-balogun-gbenro-ajibade-star-new-film-bachelors-eve.html.
- ↑ Alhassan, Amina (3 April 2010). "The Child wins 9 AMAA nominations". Daily Trust. Archived from the original on 31 July 2017. https://web.archive.org/web/20170731031115/https://www.dailytrust.com.ng/index.php/news/4948-mentally-retarded-found-among-plateau-pilgrims. Retrieved 30 July 2017.
- ↑ "See Full List Of Nominees For 2014 City People Entertainment Awards Nominees List". Information Nigeria. 8 June 2014.
- ↑ "O.C Ukeje, Gabriel Afolayan, Funke Akindele, Imeh Bishop Udoh lead nominees for Nollywood Movie Awards". Nigeria Entertainment Today. 28 September 2013.
- ↑ "AMVCA nominees announced". DStv. 12 December 2014. Archived from the original on 17 April 2015.
- ↑ "Voting opens for Nigeria Entertainment Awards 2015". The Guardian. 19 July 2015. Archived from the original on 31 July 2017. https://web.archive.org/web/20170731040530/http://guardian.ng/saturday-magazine/weekend-beats/voting-opens-for-nigeria-entertainment-awards-2015/. Retrieved 30 July 2017.