Yakubu Muhammed
Yakubu Mohammed tí wọ́n bí ní ọjọ́ kẹẹ̀ẹ́dọ́gbọ̀n oṣù Kẹ́ta ọdún 1973 jẹ́ òṣèré orí-ìtàgé, olùgbéré-jáde, adarí eré, olórin àti olùkọ̀tàn ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà. Ó tún jẹ́ aṣojú àti olùpolówó ọjà fún ilé-iṣẹ́ ìbáraẹni sòrò ti Globacom.[4] Ó tún jẹ́ aṣojú fún àjọ SDGs , ó sì tún fìgbà kan jẹ́ aṣojú fún ilé-iṣẹ́ ambassador and Nescafe Beverage.[5] Yakubu Mohammed jẹ́ ọ̀kan lára àwọn lààmì-laaka ní Kannywood àti Nollywood. Ó ti kọ orin tí ó ti lé ní ẹgbẹ̀rùn ún, ó ti kópa nínú eré rí ó ti tó ọgọ́rùn ún nínú eré Hausa. Lára rẹ ni: Lionheart, 4th Republic, Sons of the Caliphate àti MTV Shuga èyí tí ó sọọ́ di ẹni tí wọ́n fún àwọn amì-ẹ̀yẹ ọlọ́kan-ò-jọkan bí City People Entertainment Awards[6] àti Nigeria Entertainment Awards.
Yakubu Muhammed | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | 25 Oṣù Kẹta 1973 Bauchi, Nàìjíríà[1] |
Orílẹ̀-èdè | Nàìjíríà |
Ẹ̀kọ́ | Mass Communication (BSc) |
Iléẹ̀kọ́ gíga | University of Jos, Bayero University Kano[2] |
Iṣẹ́ | Film Actor, producer, director, Singer,[3] Script Writer |
Ìgbà iṣẹ́ | 1998–present |
Gbajúmọ̀ fún |
Iṣẹ́ rẹ̀
àtúnṣekannywood ni Yakubu ti bẹ̀rẹ̀ ìkòpa nínú eré ní ọdún 1998 nígbà tí ó kọ eré kan tí ó sì ṣe agbátẹrù eré náà. Nígbà tí ó yá, ó kẹ́kọ̀ọ́ síwájú si nínú iṣẹ́ tíátà, tí ó sì gòkè àgbà nínú iṣẹ́ tí ó yàn láàyò. Yakubu tún jẹ́ olórin tí ó sì ti gbé orin tí ó tó ẹgbẹ̀rún kan jáde fún àwọn eré sinimá àgbéléwò lọ́kan ò jọ̀kan àti àwọn mìíràn ní èdè Hausa àti Gẹ̀ẹ́sì, [7][8] òun àti ọ̀rẹ́ rẹ̀ tí wọ́n jọ ń ṣiṣẹ́ pọ̀ Sani Musa Danja. Ó dara pọ̀ mọ́ Nollywood ní ọdún 2016 nígbà tí ó ṣe Sons of the Caliphate pẹ́lú Ìfọwọ́sowọ́pọ̀ akẹgbẹ́ rẹ̀ kan Rahama Sadau[9] Ó tún fara hàn nínú àwọn eré bíi: MTV Shuga àti Lionheart.[10]
Àwọn eré Nollywood rẹ̀
àtúnṣeÀkọ́lé | Ọdún |
---|---|
Sons of The Caliphate[11] | 2016 |
MTV Shuga Naija[12] | 2017 |
Queen Amina[13] | |
Makeroom[14] | |
LionHeart[15] | |
Asawana | |
4th Republic[16] | |
Tenant of The House[17] | |
Dark Closet[18] | |
Fantastic Numbers[19] | |
Walking Away[20] | |
My Village Bride[21] | |
Chauffeur[22] | |
Damaged Petals[23] | |
Bunmi's Diary[citation needed] | |
Power of Tomorrow[24] | |
My Neighbor's Wife[25] | |
My Wife's Lover[26] | |
Blue Flames[27] | |
April Hotel[28] | |
Women | |
Wings of A Dove[29] |
Àwọn eré Kannywood rẹ̀
àtúnṣeCikin Waye | ND |
Gabar Cikin Gida | 2013 |
Da Kai Zan Gana | 2013 |
Mai Farin Jini | 2013 |
Nas | 2013 |
Romeo Da Jamila | 2013 |
Sani Nake So | 2013 |
Shu'uma (The Evil Woman) | 2013 |
Soyayya Da Shakuwa | 2014 |
So Aljannar Duniya | 2014 |
Sai A Lahira | 2014 |
Munubiya | 2014 |
Hakkin Miji | 2014 |
Duniyar Nan | 2014 |
Bikin Yar Gata | 2014 |
Kayar Ruwa | 2015 |
Son of Caliphate | 2016 |
Hawaye Na | 2016 |
Yar Mulki | 2016 |
Àwọn Ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ "Yakubu Mohammad [HausaFilms.TV – Kannywood, Fina-finai, Hausa Movies, TV and Celebrities]". hausafilms.tv. Retrieved 24 May 2019.
- ↑ "10 Things You Didn't Know About Yakubu Mohammed". Youth Village Nigeria. 8 April 2016. Retrieved 24 May 2019.
- ↑ Adelaja, Tayo (2 February 2018). "Ban Taba Son Waka A Raina Ba – Yakubu Mohammed". Leadership Hausa Newspapers (in Èdè Hausa). Retrieved 24 May 2019.
- ↑ "The list of Glo ambassadors according to globacom website". 16 August 2011.
- ↑ https://opera.news/ng/en/entertainment/a11c810588ee286dc585338d5111d8bb[Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́]
- ↑ "Kannywood: Yakubu Mohammed, Hannatu Bashar, five others bag awards in Lagos". Premium Times Nigeria. 25 July 2016. Retrieved 24 May 2019.
- ↑ "Dandalin Fasahar Fina-finai – Salon Rubuta Labari a Fim" (in Èdè Hausa). Radio France Internationale. 30 April 2016. Retrieved 24 May 2019.
- ↑ Lere, Mohammad (10 June 2013). "Kannywood's Yakubu Mohammed stars in 20 movies in two months". Premium Times Nigeria. Retrieved 24 May 2019.
- ↑ "sadau goes to mtv shuga". guardian.ng. The Guadian. Archived from the original on 24 May 2019. Retrieved 24 May 2019.
- ↑ Nwabuikwu, Onoshe. "Nollywood Meets Kannywood in Lionheart". Punch Newspapers. Retrieved 24 May 2019.
- ↑ "Sons of the Caliphate". Ebony life tv. Archived from the original on 12 August 2022. Retrieved 3 November 2020.
- ↑ "Kannywood stars Rahamu Sadau, Yakubu Mohammed among cast of MTV Shuga". 21 September 2017.
- ↑ "TRAILER: Izu Ojukwu's period movie on the legend of Queen Amina". Queen Amina Movie. 7 September 2017.
- ↑ "Makeroom". Mingoroom. 8 November 2018. Archived from the original on 24 May 2019. Retrieved 3 November 2020.
- ↑ "The Lion Heart". 13 January 2019.
- ↑ "4th Republic premier stuns Lagos film denizens". 4th Republic. 12 April 2019.
- ↑ "Tenants of the house".
- ↑ "Dark Closet Nollywood Movie". 23 February 2015.
- ↑ "Fantastic Numbers Nollywood Movie".
- ↑ "Walking Away Nollywood REinvented". 10 November 2016.
- ↑ "My Village Bride – Liz Benson, Patience Ozokwor,Vitalis Ndubuisi, Bobby Obodo,Calista Okoronkwo, Mohammed Yakubu.". Archived from the original on 25 May 2019. Retrieved 3 November 2020.
- ↑ "Bobby Obodo loss his right eye while on movie set with Rita Dominic". 14 January 2017.
- ↑ "damaged-petal-nigeria". 2015. Archived from the original on 28 May 2019. Retrieved 3 November 2020.
- ↑ "power-of-tomorrow-". 25 April 2015.
- ↑ "my-neighbours-wives". 16 September 2017.
- ↑ "My wifes-lover-nonso-diobi-munachi-abii- yakubu". 28 February 2017.
- ↑ "premiere-of-blue-flames/". 25 April 2013. Archived from the original on 28 May 2019. Retrieved 3 November 2020.
- ↑ "yakubu-mohammed-wins-city-peoples-best.html/April hotel". 7 August 2016.
- ↑ "zack-orji-sani-danja-yakubu-mohammed-star-omoni-obolis-wings-dove". 10 September 2018.