Yemi Shodimu
Yẹmí Ṣódìímú ni wọ́n bí ní Kọkàndínlọ́gbọ̀n oṣù Kínní, ọdún 1960 ( January 29, 1960) ní ìlú Abẹ́òkúta ní orílẹ̀-èdè a Nàìjíríà jẹ́ eléré orí ìtàgé, Atọ́kùn Ètò, Olùdarí àti Olùgbéré jáde.[1]
Yemi Shodimu | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | Ogun State, Nigeria. | 29 Oṣù Kínní 1960
Orílẹ̀-èdè | Nigerian |
Ọmọ orílẹ̀-èdè | Nigerian |
Iṣẹ́ | film actor Film director and Film maker |
Gbajúmọ̀ fún | Oleku (1997) |
Ìgbòkègbodò Ayé rẹ̀
àtúnṣeWọ́n bi ní ìlú Abẹ́òkúta, tí ó jẹ́ Olú ìlú Ìpínlẹ̀ Ògùn ní apá Ìwọ̀ Oòrùn orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.[2]Ó lo ìgbà èwe rẹ̀ ní ìlú Abẹ́òkúta í Ààfin Ọba Aláké ilẹ̀ Ẹ̀gbá ní bi tí ó ti ní àwòfín nípa àṣà Yorùbá. [3]Ó lè sí ilé-ẹ̀kọ́ kọ́wbáfẹ́mi Awólọ́wọ́ University níbi tí ó ri gba ìwé ẹ̀rí Bachelor of Arts (B.A.) , nínú ìmọ̀ ọ̀nà ìṣeré Ìtàgé ( dramatic art) , lẹ́yìn èyí ni ó tẹ̀ síwájú ní Fásitì Ìpínlẹ̀ Èkó níbi tí ó ti gba ìwé ẹ̀rí Master of Arts (M.A.) nínú ìmọ̀ Mass communication.[4]
Iṣẹ́ Òòjọ́ rẹ̀
àtúnṣeÓ bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ òṣèré rẹ̀ ní ọdún 1976, tí ó aì kópa tó lààmì laka nínú eré orí ìtàgé tí àkòrí rẹ̀ ń jẹ́ Village Head Master. Ó di ìlúmọ̀ọ́ká pẹ̀lú ipa rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí Olú ẹ̀dá ìtàn, ó tún jẹ́ Olú ẹ̀ ẹ̀dá ìtàn nínú eré orí ìtàgé tí àkòrí rẹ̀ ń jẹ́ ''' lekú''' gẹ́gè bí Àjàní nínú eré yí.[5] Túndé Kèlání ṣe adarí rẹ̀
Àwọn eré orí ìtàgé rẹ̀
àtúnṣe- Village Head Master that featured Victor Ọláòtán
- Ó Lekú (1997) láti ọwọ́ Tunde Kelani
- Ti Olúwa Ni Ilẹ̀̀
- Ṣaworo Idẹ tí Kúnlé Afọláyan àti Peter Fátómilọ́llá
- Ayọ̀ ni Mofẹ́
- Kòṣéégbé[6]
Ẹ tún le wo
àtúnṣe- Àtòjọ àwọn òṣèré ilẹ̀ Nàìjíríà
Àwọn Ìtọ́ka sí
àtúnṣe- ↑ "Meet Ayobami, Yemi Shodimu’s actress, singer and model daughter". QED.NG. 2018-02-22. Retrieved 2019-10-23.
- ↑ "Don’t mistake me for cultist because of “Oleku” movie, actor tells Nigerians". Pulse Nigeria. 2019-04-26. Retrieved 2019-10-23.
- ↑ Bodunrin, Sola (2016-03-18). "19 years after Oleku: Yemi Shodimu , Feyikemi come together again". Legit.ng - Nigeria news. Archived from the original on 2019-10-23. Retrieved 2019-10-23.
- ↑ "Yemi Shodimu Archives - Nigeria and World News". The Guardian Nigeria News - Nigeria and World News. Retrieved 2019-10-23.
- ↑ "Women age fast when left with domestic chores alone—Yemi Shodimu". Punch Newspapers. 2015-12-15. Retrieved 2019-10-23.
- ↑ "THE MOVIE ROLE THAT NEARLY RUINED MY CAREER – Yemi Shodimu". Yes International! Magazine. 2016-01-18. Archived from the original on 2019-10-23. Retrieved 2019-10-23.