Yetunde Onanuga
Yetunde Onanuga (tí a bí ní 11 September 1960) jé òtòkùlú olósèlú ní Naijiria àti ígbákejì Gomina ipinle Ògùn teleri.[1]
Yetunde Onanuga | |
---|---|
Deputy Governor of Ogun State | |
In office 2015–2019 | |
Gómìnà | Ibikunle Amosun |
Asíwájú | Segun Adesegun |
Arọ́pò | Noimot Salako-Oyedele |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọjọ́ìbí | 11 Oṣù Kẹ̀sán 1960 Ibadan, British Nigeria |
Ọmọorílẹ̀-èdè | Nigerian |
Ẹgbẹ́ olóṣèlú | All Progressives Congress (APC) |
Ayé rè
àtúnṣeA bí Onanuga ní ilé iwosan Adeoyo, ìlú Ibadan, olú-ìlú Ìpínlè Oyo, oruko baba rè ni Fabamwo [2] O koko kàwé ní ipinle ogun ko to dipe o kawe ni ìlú Eko nibi to ti gba owe eri fún isé olukoni. O pada tèsíwájú lati gba àmì-èye MBA ni yunodasoti ipinle Ogun. Oun sise pelu ijoba ipinle eko Lori oro adugbo nígbà tí a yan láti díje pèlú Ibikunle Amosun ni odun 2015. Ígbákejì ibikunle Amosun nígbà sáà àkókò rè ti lp sí egbe oselu míràn, Amosun yan Onanuga larin awon méta.[3] A yan Onanuga sípò ígbákejì Gomina labe egbe oselu APC.
Àwon Ìtókasí
àtúnṣe- ↑ "Onanuga emerges new Ogun deputy governor". Daily Trust. 2014-12-16. Retrieved 2022-05-30.
- ↑ "Onanuga: Round peg in round hole". The Nation Newspaper. 2015-01-07. Retrieved 2022-05-30.
- ↑ "How Amosun’s running mate emerged". Vanguard News. 2014-12-18. Retrieved 2022-05-30.