Olayinka Joel Ayefele MON jẹ́ ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà àti akọrin Ìhìnrere ní ìlànà Kìrìsìtẹ́nì.[2][3] Ó sì tún jẹ́ olóòtú ètò orí rédíò, àti olùdásílẹ̀ Fresh àti Blast FM, tó wà káàkiri apá Ìwọ̀-oòrùn ilẹ̀ Nàìjíríà.[4][5][6]

Yinka Ayefele
Yinka Ayefele ńkọ orin nibi ayeye kan ni Ìpínlẹ̀ Ògùn
Ọjọ́ìbíỌláyínká Joel Ayéfẹ́lẹ́
1 Oṣù Kejì 1968 (1968-02-01) (ọmọ ọdún 56)
Ipoti-Èkìtì, Nàìjíríà
Orílẹ̀-èdèỌmọ Nàìjíríà
Ọmọ orílẹ̀-èdèNàìjíríà
Iṣẹ́Olórin
Ìgbà iṣẹ́1998–títí di àsìkò yìí
Olólùfẹ́Temitope Titilope[1]
Parent(s)Chief Joshua Taiwo Ayefele (Father)[1]

Ìbẹ̀rẹ̀pẹlpẹ̀ ayé rẹ̀

àtúnṣe

Wọ́n bí Ayefele Ipoti-Ekiti, èyí tó jẹ́ ìlú kan ní Ìpínlẹ̀ Èkìtì, tó wà ní apá Ìwọ̀-oòrùn ilẹ̀ Nàìjíríà[7]

Ètò Ẹ̀kọ́

àtúnṣe

Ilé-ìwé Our Saviours Anglican Primary School ní Ipoti-Ekiti ló lọ fún ẹ̀kọ́ ìbẹ̀rẹ̀ àti ẹ̀kọ́ girama, kí ó tó lọ sí Ondo State College of Arts and Science ní Ikare Akoko, tó wà ní Ìpínlẹ̀ Òndó, Nàìjíríà.[8]

Iṣẹ́ tó yàn láàyò

àtúnṣe

Ayefele ṣiṣẹ́ fún ìgbà díẹ̀ gẹ́gẹ́ bí i akọ̀ròyìn àti agbéròyìnjáde ní Federal Radio Corporation of Nigeria, Ibadan, níbi tí ó sì máa ń ṣàgbéjáde orin kékèèké lórí rédíò.[9] Ó bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ orin tó yàn láàyò ní ọdún 1997 lẹ́yìn tí ó farapa ní ìjàm̀bá ọkọ̀ tó bá eegun ẹ̀yìn rẹ̀ jẹ́, tí ó sì mu kí ó wà ní orí wheelchair.[10][11] Nígbà tó ṣì wà ní ilé-ìwòsàn níbi tí ó ti lo bí i oṣù mẹ́sàn-án, ọ̀rẹ́ rẹ̀ Kola Olootu, bẹ̀ ẹ́ wò, ó sì gbà á níyànjú pé kí ó hun àwọn orin kan pọ̀.[12] Ìyànjú yìí ló bí àwo-orin Bitter Experience ní ọdún 1998, tó sì mú u wá sí gbàgede.[13] Àgbéjáde àwo-orin Sweet Experience ló tẹ̀lé orin Bitter Experience.[14] Àwọn àwo-orin ìmíì tó ti ọwọ́ akọrin yìí jáde ni Something Else, Divine Intervention àti Life after death, tí ó gbé jáde láti fi ṣẹ̀yẹ Gbenga Adeboye, tó jẹ́ olóòtú ètò orí rédíò, olórin àti apanilẹ́rìn-ín.[15] Orin Bitter Experience ṣàpèjúwe àwon ìrírí rẹ̀, Sweet Experience sì jẹ́ "adùn tó gbẹ̀yìn ewúro rẹ̀".[16]

Àtòjọ àwọn àmì-ẹ̀yẹ rẹ̀

àtúnṣe

Ayefele ti gba àmì-ẹ̀yẹ tó lé ní igba.[17] Lára wọn ni:

 
Yinka Ayefele music house ado ekiti

Àtòjọ àwọn orin rẹ̀

àtúnṣe
  • Bitter Experience (1998)
  • Sweet Experience (1999)
  • Something Else (2000)
  • Divine Intervention (2001)
  • Fun Fair (2002)
  • Life after Death (2003)
  • Aspiration (2003)
  • Fulfilment (2004)
  • New Dawn (2005)
  • Next Level (2006)
  • Gratitude (2007)
  • Absolute Praise (2008)
  • Transformation (2009)
  • Everlasting Grace (2010)
  • Prayer Point (2011)
  • Goodness Of God (2012)
  • Comforter (2013)
  • Overcomer (2014)
  • Upliftment (2015)
  • Fresh Glory (2016)
  • Living Testimony (2017)
  • Favour (2018)
  • Beyond The Limits (2019)
  • Ekundayo (Exhilaration) (2020)
  • Manifestation (2021)
  • So Far So Good (2022)

Àwọn ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. 1.0 1.1 Our Correspondent. "New Telegraph – How Yinka Ayefele's father died after birthday celebration". newtelegraphonline.com. Archived from the original on 11 February 2015. Retrieved 11 February 2015. 
  2. "Yinka Ayefele's travails". The Punch – Nigeria's Most Widely Read Newspaper. Archived from the original on 11 February 2015. Retrieved 11 February 2015. 
  3. "Yinka Ayefele celebrates". The Punch – Nigeria's Most Widely Read Newspaper. Archived from the original on 11 February 2015. Retrieved 11 February 2015. 
  4. "Nigeria's Fresh FM radio station partially demolished following critical reporting". Committee to Protect Journalists (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2018-08-27. Retrieved 2021-03-13. 
  5. "Yinka Ayefele's travails". The Punch – Nigeria's Most Widely Read Newspaper. Archived from the original on 11 February 2015. Retrieved 11 February 2015. 
  6. "Yinka Ayefele celebrates". The Punch – Nigeria's Most Widely Read Newspaper. Archived from the original on 11 February 2015. Retrieved 11 February 2015. 
  7. "Shock as Yinka Ayefele's father dies at birthday party – DailyPost Nigeria". DailyPost Nigeria. 15 October 2014. Retrieved 11 February 2015. 
  8. "Yinka Ayefele discusses his accident, marital life, Patience Jonathan rally and music in new interview". dailystar.com.ng. Archived from the original on 23 October 2013. Retrieved 11 February 2015. 
  9. "Yinka Ayefele Bereaved As Late Father Wanted Him To Be A Banker". nigeriafilms.com. Retrieved 11 February 2015. 
  10. "The incredible lifestyle of an entertainer". Vanguard News. 24 August 2014. Retrieved 11 February 2015. 
  11. Emokpae Odigie (2015). When Reasoning Is on Vacation. Strategic Book Publishing & Rights Agency. p. 77. ISBN 9781631351914. https://books.google.com/books?id=j6a8BwAAQBAJ&pg=PA77. 
  12. "Yinka Ayefele: What The President's Handshake Did To Me, Articles – THISDAY LIVE". thisdaylive.com. Archived from the original on 11 February 2015. Retrieved 11 February 2015. 
  13. "People Take Advantage of My Condition----Yinka Ayefele". modernghana.com. Retrieved 11 February 2015. 
  14. "Yinka Ayefele to release new album in January 2015". Nigerian Entertainment Today – Nigeria's Number 1 Entertainment Daily. Retrieved 11 February 2015. 
  15. "Yinka Ayefele – Gbenga Adeboye Life after death". Last.fm. Retrieved 11 February 2015. 
  16. Administrator. "About Yinka Ayefele". ayefeleradio.com. Archived from the original on 11 February 2015. Retrieved 11 February 2015. 
  17. "HISTORIC: HONOR NIGHT IN TORONTO! Ayefele Bags 200th Award in Canada…Receives Special Lifetime Achievement Award * Nigeria Embassy Officials to witness Ceremony * Sir Shina Peters as Special Guest!". nigeriastandardnewspaper.com. Archived from the original on 11 February 2015. Retrieved 11 February 2015.