Yoruba Ronu
Yoruba Ronu tàbí Yorùbá Ronú lè jẹ́;
- Àkọlé orin tí Olóògbé Hubert Ogunde kọ lọ́dún 1964.[1]
- Gbajúmọ̀ gbólóhùn láti pé ènìyàn, pàápàá ọmọ Yorùbá sí àkíyèsí nípa ìwà ìbàjé tàbí ohun tí kò dára pẹ̀lú èròǹgbà fún àtúnṣe
- Gbólóhùn tí ó túmọ̀ sí pé kí ọmọ tàbí ìran Yorùbá máa ronú.[2]
Àwọn Ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ "Yoruba Ronu". Daily Trust. 2021-03-29. Retrieved 2024-07-08.
- ↑ "work by Ogunde". Encyclopedia Britannica. 1971-03-12. Retrieved 2024-07-08.